Sodiq Kolayo Translation of the book - maqsuratu ibn dureid (مقصورة ابن دريد) into English and Yoruba languages 26-Jun-2020Translation-of-the-second-10-stanzas-to-English alt=

Translation of the second 10 stanzas to English


إِذا ذَوى الغُصنُ الرَطيبُ فَاعلَمَـن أَنَّ قُـصـاراهُ نَـفـاذٌ وَتَـــوى

If a succulent branch of a plant dried, just be cognizant that it will soon break and lost.

Nígbàtí ẹtúntún ígí bá tí rọọ́, wá lọ́ mọ pé dájúdájú péé ohùn tí yóò gbẹ̀yín rẹ ní títán atí ìpárùn.

شَجيتُ لا بَـل أَجرَضَتنـي غُصَّـةٌ عَنودُها أَقتَـلُ لـي مِـنَ الشَجـى

I appeared sorrowful; rather, I was choked by a bone that is obstinate to kill than the sorrow.

Ínú mí bàjẹ́, àmọ́ égún kán ló hámí lọ́rùn, títàkú rẹ yàrá pánì jú ìbànújẹ náà lọ́.

إِن يَحم عَن عَيني البُكـا تَجَلُّـدي فَالقَلبُ مَوقوفٌ عَلى سُبـلِ البُكـا

If my flexibility wipeout tears from my eyes, Just know that my heart is on the way to cry.

Tí àmúmọ́rà mí bá kọ̀ fún ojú mí láti sún ẹ́kùn, ẹ́lọ́mọ pé ọkàn mí ńbẹ́ láwọn ojú ọnà ẹ́kùn.

لَو كانَـتِ الأَحـلامُ ناجَتنـي بِمـاأَلقـاهُ يقظـانَ لأَصمانـي الـرَدى

If dreams had revealed to me what am facing in reality, I would have died in it.

Tó bá ṣépé àwọn àlá mí tí sáájú ṣàlàyé óhùn tí mó ǹbápàdé lójú ìrán fún mí ní, ǹbá tí kú sójú órún.

مَنزلةٌ مَـا خِلتهـا يَرضـى بِهـالِنَفـسِـهِ ذو أرَبٍ وَلا حِـجــى

It is a horrible state, that I don't think a smart and clever person will desire.

Ìpó kán ní, ti mìò lérò pé ọ̀jọ̀gbọ́n kan tàbí òní làákàyè kan yíò yọnú sí fún ẹ̀mí árárẹ̀.

شيـمَ سَحـابٍ خُـلَّـبٍ بـارِقُـهُ وَمَوقِـفٌ بَيـنَ اِرتِجـاءٍ وَمُـنـى

My ambitions Are now like sighting, a cloud with capricious lightning. And a position of uncertainty.

Awọ́n èròngbà mí wá dà gẹgẹ bí wíwo ẹ̀súsú òjò kán, tí ìtàn yànràn etímọ́ rẹ̀ ńtàn nìjẹ́. Ati ìpele írókàn aàtí eróngbà.

فـي كُـلِّ يَـومٍ مَنـزِلٌ مُستَوبـلٌ يَشتَفُّ مـاءَ مُهجَتـي أَو مُجتَـوى

I found myself every day in an objectionable or undesirable state, sucking out my blood

Lójójùmọ́ ní mó ńbà rámí nipo tí mío fẹ́, tó sìn fún ómí ẹmímí mù, tàbí ipò tí kò bámi lára mùú.

ما خِلتُ أَنَّ الدَهـرَ يُثنينـي عَلـى ضَرّاءَ لا يَرضى بِها ضَبُّ الكُـدى

I couldn't believe that this time will harm me, to an extent that even an uromastyx (spiny-tailed lizard) of the desert will dislike it.

Míò lé rò wípé, ìgbà lè darímì lọ sí íbí ìnírá, tí Agílíntí orí pápá gán kólé yọ̀nú síi.

أُرَمِّقُ العَيشَ عَلـى بَـرضٍ فَـإِن رُمتُ اِرتِشافاً رُمتُ صَعبَ المُنتَهى

I live a satisfactory life with dewlike moisture. If I desire to take a sip, it becomes difficult.

Mo ńyọ́ ìgbésí ayé mí lo, pẹlú emímí ómì. tí mó baà lè rò atí mú púpọ, mo ńgberó ìnírá ní yẹ́n.

أَراجِعٌ لـي الدَهـرُ حَـولاً كامِـلاً إِلـى الَّـذي عَـوَّدَ أَم لا يُرتَجـى

Will the days return a full year, to the one that is uncomplicated or it should not be expected?

Ǹjẹ́ ìgbà lè dá ódìndìn ọ́dún kàn pàdà wàá, sí èyí tí óbáwá lárámù, àbí kí wọn máa ré tìrẹ̀ ?.

WRITTEN IN ARABIC BY:

IBN DUREID.

TRANSLATED BY:

S.A KOLAYO.

4 likes 963

share : whatsapp share


You must be logged in to contribute to discussions here !