Sodiq Kolayo Translation of the book - maqsuratu ibn dureid (مقصورة ابن دريد) into English and Yoruba languages 03-Aug-2020Translation-of-the-sixth-ten-stanzas-of-Maqsurat-ibn-Dureid-(مقصورة-ابن-دريد) alt=

Translation of the sixth-ten stanzas of Maqsurat ibn Dureid (مقصورة ابن دريد)


Arabic - بَرٍّ بَرى طـولُ الطَـوى جُثمانَـهُ فَهوَ كَقَـدحِ النَبـعِ مَحنِـيُّ القَـرا

English - They do carry every good person that was skinned by a long starvation, and He appeared as a darting arrow bent at the back.

Yoruba - Tí wọ́n gbé pọ̀n gbógbó èyánré, tí ebí àpájù tí gbẹ́ árá wọ́n, tí wọ́n wá dà gẹgẹ bí ọ́rùn ọ́fà tí ó tẹ̀ lẹyìn.

Arabic - يَنوي الَّتـي فَضَّلَهـا ربُّ العُلـى لَمّـا دَحـا تُربَتَهـا عَلـى البُنـى.

English - He intended to visit what was graced by the Lord of the Highness when He(Almighty) had layed its soil on the structure.

Yoruba - Óngbèró áayè tí Ọ́bá gígá gbé ọ́lá fún, nìgbà tí ó tí tẹ̀ ìyẹ́pẹ̀ rẹ̀ lórí mímọ́ ilé náà.

Arabic - حَتّـى إِذا قابَلَـهـا اِستَعـبَـرَ لا يَملِكُ دَمعَ العَينِ مِن حَيـثُ جَـرى

English - Till when he(traveller) faced the building and cried, and was unable to hold the tears of his eyes from its source.

Yoruba - Títí dìgbà tí ó fì kọ́jù sí ilé náà tí ó wá bú sẹ̀kún, tí kò lágbára àti dáwọ ẹ́kùn náà níbí tó ntì ṣọ̀n wá.

Arabic - فَأوجَـبَ الحَـجَّ وثَنّـى عـمـرة مِن بَعدِ مـا عَـجَّ وَلَبّـى وَدَعـا

English - He engaged in the greater pilgrimage (Hajj) and observed the lesser pilgrimage (U'mrah) secondly, after he had cried to Almighty, answered the divine call and prayed.

Yoruba - Ó wá ṣé ìṣẹ́ Hájì ó tún wá fí Ùmráh ṣe ẹ̀lẹ́kéjì, lẹ̀hìn ìgbàtí ó tí sún ẹ̀kún sí ọ́lọ̀hún, tí otún tí jẹ́ ìpé rẹ̀, tí otún wá ṣé àdúà.

Arabic - ثُمَّـتَ طـافَ وَاِنثَنـى مُستَلِـمـاًثُمَّـتَ جـاءَ المَروَتَيـنِ فَسَـعـى

English - Then he toured around and returned while greeting the Black stone, then he arrived for the Sofa and Morwa and jogged.

Yoruba - Lẹhìn náà ló wá ṣé táwàf, ó wá pádà lẹ́nì tón kí Òkúta dúdú, lẹhìn ló wà pọ́ ṣẹ̀ṣẹ̀ làrin Sọ̀fá atí Mọ̀rwá.

Arabic - ثُمَّـتَ راحَ فـي المُلَبّيـنَ إِلــى حَيـثُ تَحَجّـى المَأزمـانِ وَمِنـى.

English - Then he lately joined the congregation of the observers where the people of the Mahazmani and Mina invoke their pilgrimage.

Yoruba - Lẹhìn ìgbà náà ló wá lọ kún àwọn tí wọn ńṣé làbáikà lálẹ̀, níbí tí àwọn ará Màházìmánì àti Mìná tí màá ńṣè Hájì.

Yoruba - ثُمَّ أَتـى التَعريـفَ يَقـرو مُخبِتـاًمَواقِـفـاً بَـيـنَ أُلالٍ فَالـنَـقـا

English - Then he went to Mount Arafat walking with contentment, and waited between Hùlál and white sand

Yoruba - Lẹyìn náà ló wá gún Àràfá lẹ́ní tí ntọ́ ojú ọnà pẹlú ìtẹ́ríbá, tí ó wá kórá dúró láàrin Hùlál àti íyẹ̀pẹ́ fúnfún.

Arabic - ثُـمَّ أَتـى المَشعَـرَ يَدعـو رَبَّـهُ تَضَرُّعـاً وَخُفيَـةً حَتّـى هَـمـى

English - Then he came to Masha'r, beseeching his God with supplication and silently until he wept.

Yoruba - Lẹhìn náà ló lọ̀ sí Màṣà'r lẹ ní tín bẹ̀ Ólọ̀hún pẹlú ìjírẹ̀bẹ̀ títí tó fí sún ẹkùn.

Arabic - وَاِستَأنَفَ السَبـعَ وَسَبعـاً بَعدَهـا وَالسعيَ ما بَينَ العِقابِ وَالصُـوى.

English - And he resumed back to aiming of stones against the devil seven times and another seven turns after that, and jogged between the I'qab and Suwa.

Yoruba - Ó wá dárí sí sísọ́ òkò àṣétánì lẹ méje atí méje míràn lẹyìn náà, ó wá pọ ṣẹ̀ṣẹ̀ làrin ààyè Ì'qáb atí Sùwá.

Arabic - وَراحَ لِلتَوديـعِ فيمَـن راحَ قَــد أَحرَزَ أَجـراً وَقَلـى هُجـرَ اللغـا

English - He then resorted to the bidding of farewell among others, while he had conserved gains and abandoned the offensive word.

Yoruba - Ó wà lálẹ́ síbí ìdágbèré pápọ̀ mọ́ àwọn èyán tó kù, lẹ̀ní tí otí kó èrè tópọ̀ tí ó sì tún tí kọ́ ọ̀rọ̀ èébú sílẹ.

7 likes 3,755

share : whatsapp share


You must be logged in to contribute to discussions here !

2 comments found ...

comments and thoughts yusuf olalekan 03-Aug-2020 Nice ! 👍👍👍

1 like


comments and thoughts Abdullateef Busairy 03-Aug-2020 Why not sharing to your Facebook page ? 📖

People can quickly know from their when you updated this page 😁

2 likes 1