Sodiq Kolayo Translations of the book - maqamat-al-hareeri into English and Yoruba 26-Aug-2020CONTINUATION-OF-THE-23RD-ASSEMBLY-OF-HARIRI alt=

CONTINUATION OF THE 23RD ASSEMBLY OF HARIRI


قال فبرز الشيخ مجليا و تلاه الفتى مصلّيا،

-Then started forth the old man as the winning horse, while the boy followed him like the second in the course,

Bàbá àgbàlagbà náà wá jáde sí ìtá gẹgẹ bí ẹ̀ṣìn tí ó ṣàjú, tí ọ̀dọ́(ọ̀mọ̀) náà sì tẹlé gẹgẹ bí ẹ̀ní Kejì níbí ìdíje,

و تجاريا بيتا فبيتا على هذا النسق إلى أن كمل نظم الأبيات واتسق:

And they both raced together stanza by stanza in this order, until the series of stanzas was perfected and made up:

Wọ́n jọ̀ wá ń fì ẹ̀sẹ̀ órín kán kán jágbà láàrín àráwọ̀n lórí ìlànà yìí, títí ẹ̀sẹ̀ órín náà fíì pèé, tí ó sí dáàrà:

وهي

وأحوى حوى رقّي برقة ثغره

و غادرني إلف السهاد بغدره

Old Man: There is a ruddy lipped one who has compassed my enslaving with the delicacy of her utterance, and left me in company with sleeplessness through her perfidy,

Bàbá: elétè pùpá kán tí kó ìmúnísìn míì ní pàpà mọ̀rá pẹ̀lú pẹ̀lẹ̀pẹ̀lẹ̀ ọ̀rọ̀ ẹ̀nú rẹ, tí ó sì tún wá pàmítì láì kò rí orùn sùn pẹ̀lú ìwà ọ̀dàlẹ̀ rẹ,

تصدى لقتلي بالصدود و إنني

لفي أسره مذ حاز قلبي بأسره

Youth: She has attempted to slay me by her aversion, truly am in her bond since she has gotten my heart altogether,

Ọ̀dọ́: Ó tí gbìyànjú là tí pámìí pẹlú ìtákò rẹ, ṣùgbọ́n dájúdájú mó tí kò sí pànpẹ́ rẹ̀, làtí ìgbàtí ó tí jèéré ọ̀kàn mí làpáàpọ̀,

أصدّق منه الزّور خوف ازوراره

و أرضى استماع الهجر خشية هجره

Old Man: I believe in her falsehood for fear of her turning from me, I am content to listen to her folly in other not to stay away,

Bàbá: Èmí gbàgbọ́ nínú ìrọ́ rẹ̀ l'ẹ̀ní tí ń pàyà ìkúrò lọ̀dọ̀mí rẹ̀, mó sì tún yọ̀nú sí gbígbọ́ ọ̀rọ̀ àgọ̀ rẹ̀ l'ẹ̀ní tí ń pàyà ìkọ̀mísílẹ̀ rẹ̀,

و أستعذب التعذيب منه و كلما

أجد عذابي جد بي حب بره

Youth: I deem her tormenting to be sweet, and as often as she renews my torment, the love of being kindly to her is renewed in me,

Ọ̀dọ́: Èmí wá sọ̀ ìyà dí ohùn tí ó dùn, àtí pé gbógbó ìgbà tí ó bá tí ṣe àtúnṣe sí ìjìyà mí, ní ìfẹ́ mí sí má tún pọ̀ síì.

تناسى ذمامي و التناسي مذمة

و أحفظ قلبي وهو حافظ سره

Old Man: She is forgetful of my promise, and forgetfulness is a fault, she angers my heart,- the heart which guard her secret.

Bàbá: Òlùgbàgbé àdéhùn míì ní, ìgbàgbé sì jẹ́ àṣìṣe, ó wá ń mú ọ̀kàn mí bìnú, - tí ó sì jẹ́ òlùṣọ́ àṣìrí rẹ̀,

و أعجب ما فيه التباهي بعجبه

و أكبره عن أن أفوه بكبره

Youth: What Is most wonderful in her is the glory of her vanity, yet I do make too much of her for me to speak to her of her pride,

Ọ̀dọ́: òhun tí ó jọ̀ní l'ojú jùlọ́ òhun ní wíwá ògo níbí àsán rẹ̀, èmí màá ń pàtàkì rẹ̀ làtí bá sọ̀rọ̀ nípá ìgbérágá rẹ̀,

له مني المدح الذي طاب نشره

ولي منه طي الود من بعد نشره

Old Man: From me she has sweet praise of fragrance, but my lot for her is a folding up of love after its out-spreading,

Bàbá: làtí ọ̀dọ̀ mí èmí ní ẹ̀yìn kán fún tí ó ṣe pé àtẹ́gùn rẹ̀ ní òórùn dídùn, mó sì tún ní làtí ọ̀dọ̀ mí fún kìká ìfẹ́ l'ẹ̀hìn títànká rẹ̀,

و لو كان عدلا ما تجنى و قد جنى

علي و غيري يجتني رشف ثغره

Youth: "If she were just she would not be fault-finding, but she wrongs me while another is gathering the dew of her mouth,

Ọ̀dọ́: Tí ó bá jẹ́ óní dédé nì kò bá má kàá  ẹ̀ṣẹ̀ sí mí lọ̀rùn, ṣùgbọ́n ó tí takò míì tí ẹ̀lòmíràn sí ń jẹ èrè òmí ẹ̀nú rẹ,

و لولا تثنيه ثنيت أعنتي

بدارا إلى من أجتلي نور بدره

Old Man: If not for her graceful motion, I would have turn rein in haste to another, the light of whose full moon I might look upon,

Bàbá: Tí kí bà ṣe tí ìgbìyànjú ọ̀pẹ́ rẹ̀ èmí à tí yàrá gbé àwọ́n ìjánú mí lọ̀bá ìmọ́lẹ̀ òṣùpá tí ó dégbá tí mó lè ṣe ànfàní làtí àrà rẹ̀,

و إني على تصريف أمري و أمره

أرى المر حلوا في انقيادي لأمره

Youth: but notwithstanding the discordance between me and her, I hold the bitter as sweet through me docility to her command,

Ọ̀dọ́: Àmọ́ l'orí pé ìjà wà láàrín èmí àtí ẹ̀, èmí rí òhùn tí ó kòórò sí àdùn níbí títẹ̀lé àṣẹ́rẹ̀,

فلما أنشداها الوالي متراسلين بهت لذكاءيهما المتعادلين

Now when in alternation they have recited the stanzas for the Governor, he was amazed at the wit of the two so much balanced,

Nìbáyìí tí àwọ́n méjèjì tí kọ́ àwọ́n ẹ̀sẹ̀ órín náà fún Gómìnà, ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fún níbí pípé làákàyè wọ́n,

و قال أشهد بالله أنكما فرقدا سماء و كزندين في وعاء

And said: "I testify before Allah that both of you are the Farkadan of the heaven, and like a pair of fire-staves in their case,

Ò wá sọ̀ pé: "Mó jẹ̀rí pẹ̀lú Ọ̀lọ̀hun pé dájúdájú ẹ̀yìn méjèjì jẹ́ ìràwọ̀ Fàrkàdánì ọ̀rún, ẹ̀ tún dà gẹgẹ bí ògùná méjì nínú àpopo wọ́n,

و أن هذا الحدث لينفق مما آتاه الله و يستغني بوجده عمن سواه،

Now surely this youth, he spends of what God has given him, through his own wealth he is independent of another,

Àtí pé dájúdájú ọ̀dọ́ yìí, ó tí ná nínú òhún tí Ọ̀lọ̀hún fún, ó tí wá rọ̀ ọ́rọ̀ pẹlú ọ̀lá rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ ẹ̀lòmíràn,

فتب أيها الشيخ من اتهامه و ثب إلى إكرامه،

So, Old Man, repent of your suspicion of him, and turn to honouring him,

Nìbáyìí, ìwọ́ bàbá àgbàlagbà, rònúpìwàdà kúrò níbí ìkẹ́fìn sí, kí ó sì tún yípadà lọ ṣé àpónlé fún,

فقال الشيخ : هيهات أن تراجعه مقتي أو تعلق به ثقتي،

Said the old man: "Far be it for my love should return to him, or my confidence cleave to him,

Bàbá àgbàlagbà náà wá sọ̀ pé: "Láàyé Láàyé ìfẹ èmí kò ní dárí sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ mọ́, ìgbáràlé míì kò sí lè rò pápọ̀ mọ̀ọ́,

و قد بلوت كفرانه للصنيع و منيت منه بالعقوق الشنيع،

For I have proved his ingratitude for kindness, I have been tried by him with shameful revolt,

Torí pé ìwà àímóre ní ò má ń fí sàn ìwà dáadáa míì, èmí tí kàn àdánwò pẹ̀lú ìṣọ́tẹ̀ àláìnítìjú rẹ̀,

فاعترضه الفتى و قال يا هذا إن اللجاج شؤم و الحنق لؤم و تحقيق الظنة إثم و إعنات البريئ ظلم،

But the youth interrupted him and said:

" O you, know that argument is ill luck, and anger offensive, to hold suspicion as truth is a sin, to annoy the innocent is a wrong,

Ọ̀dọ́ náà wá já ọ̀rọ̀ mọ́ lẹ̀nú pé: "Mó pé ìwọ́, lọ́ mọ̀ pé àríyànjiyàn kò ní èrè nínú, ìbínú sì jẹ́ ìwà ẹ̀ṣẹ̀, kí á mà pé ìfúrá ní òtítọ jẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀, kí á sì tún wá ìbínú àláìṣẹ̀ jẹ̀ ohùn tí kò dára,

وهبني اقترفت جريرة أو اجترحت كبيرة

And granted that I have committed an offence, and wrought a crime,

Wá yọ̀ndá fún mí torí pé mó tí ṣẹ̀ tàbí dá ọ̀ràn,

إما تذكر ما أنشدتك لنفسك في إبا أنسك؟

Have you remember what you yourself chanted for me in the season of your familiarity?

Ṣe ìwọ́ kò rántí órín tí ó kọ́ fúnra rẹ fún mí ní àsìkò ìfáràmọ́ rè nì?

سامح أخاك إذا خلط

منه الإصابة بالغلط

Pardon your brother when he mingles his right with error,

Ṣé àmójù kúrò fún ọ̀mọ́ ìyá rẹ̀ nígbàtí ó bá dá ohùn tí ó tọ̀nà pápọ̀ mọ́ àṣìṣe,

و تجاف عن تعنيفه

إن زاغ يوما أو قسط

And abstain from rebuking him if he went astray or decline,

Wá ṣe àmójú kúrò fún nígbàtí ó bá ṣìnà tàbí tí ó bá ṣe àbòsí,

واحفظ صنيعك عنده

شكر الصنيعة أم غمط

Keep to your kindness towards him, whether he thank the kindness or denied it,

Wá ṣọ́ ìwà dáadáa rẹ l'ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó dúpẹ fún dáadáa náà ní tàbí ó kọ̀ ọ́

و أطعه إن عاصى وهن

إن عز وادن إذا شحط

Be obedient when he revolts, be lowly when he magnifies himself, draw near to him when he goes from you,

Ṣègbọràn tí ó bá dàràn, kí ó wá tẹ̀ribá tí ó bá ṣe ìgbéraga, kí ó wá sùnmọ̀ lásìkò tí ó bá jìnà,

واقن الوفاء ولو أخل

بما اشترطت وما اشترط

Keep promise even though he fails what you and him had stipulated,

Ṣọ́ àdéhùn kó dà bí ó bá yàpà ohùn tí ìwọ́ pẹlú rẹ̀ tí fẹ̀nú kò síì,

واعلم بأنك إن طلبت

مهذبا رمت الشطط

And know that if you seek a perfect man, you have desired beyond bounds,

Wá lọ́ mọ̀ pé bí ó bá ń wá èèyàn pìpe, ó tí gbèrò kọjá àlà,

من ذا الذي ما ساء قط

ومن له الحسنى فقط

Who is there who has never done bad, who is there whose deed is always fair?

Tání èèyàn tó ṣe pé kò ṣe ìbàjẹ́ rí, atí pé tání ó jásì pé gbógbó ìwà rẹ̀ dáradára ní?

أو ما ترى المحبوب

والمكروه لزا في نمط

Or haven't you see the loved and the hated linked together in one class.

Àbí ìwọ́ kò rí ibì tí wọ́n tí só èèyàn tí á fẹràn àtí èèyàn tí á kò fẹràn pọ̀ sí òjú kàn?

كالشوك يبدو في الغصو

ن مع الجنيّ الملتقط

As the thorn comes forth on the branches with the fruit that is gathered,

Gẹgẹ bí ìgí ẹ̀gún tí ó jáde sí ẹ̀ká pẹ̀lu èsó tí wọ́n kó jọ

ولذاذة العمر الطو

يل يشوبها نغص الشمط

And the delight of long life, that mingles with it the trouble of hoariness,

Pẹlú ìdùnnú ẹ̀mí gígùn tí wàhálà ewú orí dà pápọ̀ mọ́,

و لو انتقدت بني الزما

ن وجدت أكثرهم سقط

If you examine well the sons of this era, you will noticed that most of them has fall,

Tí ó bá ṣe ìwádìí àwọ́n ọ̀mọ̀ àsìkò yìí, ó tí wípé púpọ wọ́n tí ṣùbú,

فوجدت أحسن ما يرى

سبر العلوم معا فقط

And I perceived the most pleasant that was seen, as the exploration of knowledge only,

Mó wá rí pé èyí tí ó dára jù lọ́ tí àwọ́n èèyàn rí ní ìwádìí àwọ́n mímọ nìkan,

قال فجعل الشيخ ينضنض نضنضة الصل و يحملق حملقة البازي المطل،

Then began the old man to dart as darts the serpent, and to gaze as the gazing of the towering hawk,

Bàbá náà wá bẹ̀rẹ̀ sí ní yí àhọ́n rẹ gẹgẹ bí éjò, tí ó sí ń yí ojú rẹ kírí gẹgẹ bí ẹ̀yẹ̀ àṣá tí ó fẹ́ bà,

ثم قال و الذي زين السماء بالشهب و أنزل الماء من السحب،

And he said: "I swear by him who have adorned the heaven with its fires, and sent down its water from the cloud,"

Ó wá sọ̀ pé: "Mó búrà pẹlú Ọlọhùn tí ó ṣe ẹ̀ṣọ́ sí ojú ọ̀run, tí ó sí tún sọ̀ kàlẹ̀ òmí rẹ làtí inú àwọ́n òfurufú,

ما روغي عن الاصطلاح إلا لتوقي الافتضاح

Truly my declining from reconciliation is but from fear of ignominy,

Mìò kọ̀ làtí gbà ṣùgbọ́n torí pé mó ń pàyà  àbùkù,

فإن هذا الفتى اعتاد أن أمونه و أراعي شؤونه

Because this lad is accustomed that I should provide food for him, and have regard to his affairs,

Torí pé dájúdájú ọ̀mọ́ yìí tí fẹràn kí èmí má gbé oúnjẹ wá fún, kí sì ṣe àkó lekàn ọ̀rọ̀ ààyè rẹ̀,

و قد كان الدهر يسح فلم أكن أشح،

And before fortune poured plenteously, and I was not a niggard,

Ìgbà tí gbè míì gbẹ́dẹ́múkẹ́, èmí náà kò sí jẹ́ áhún,

فأنا الآن فالوقت عبوس و حشو العيش بوس،

But as for now, the time is frowning, and the contents of life are misery,

Àmọ́ nìbáyì, ìgbà tí ń kànrá, gbógbó ǹkàn ìgbádùn ayé tí ṣòro,

حتى أن بزتي هذه عارة و بيتي لا تطور به فأرة،

So that this my garb is a loan, and my house not a mouse approaches it,

Ó wá búrú dé'bí pé àṣọ́ mí yìí àwìn nìí,

Ìlé mí ekú ò kí jẹ̀ lọ́ íbẹ̀,

قال فرقّ لمقالهما قلب الوالي و أوى لهما من غير الليالي،

Then the heart of the Governor grew tender at their speech, and he was pitiful to them because of the changes of their life,

Nìbáyìí ní ọ̀kàn Gómìnà náà wá rọ̀ fún ọ̀rọ̀ àwọ́n méjèjì, ó wá kàánù wọ́n fún ìyípadà ìgbésí ayé wọ́n,

و صبا إلى اختصاصهما بالإسعاف و أمر النظارة بالإنصراف،

And he declined to distinguish them by his help, and he bade the lookers to go away,

Ó wá jẹ̀rán làtí ṣe ẹ̀ṣà àwọ́n méjèjì pẹlú ìrànlọ́wọ́, ó wá pá àṣẹ́ kí àwọ́n ólùwórán má lọ́,

قال الراوي و كنت متشوفا إلى مرأى الشيخ لعلي أعلم علمه إذا عاينت وسمه،

Said the Narrator: "I had been gazing at the face of the old man, that perchance I might get the knowledge of him

when I should spy his features,"

Ólùpá ìtàn náà wá sọ̀ pé: "Mó wá ń wò ojú bàbá àgbàlagbà náà, bóyá mó lè mọ̀ mímọ rẹ nígbàtí mó bá dàmọ̀,

ولم يكن الزحام يسفر عنه و لا يفرج لي فأدنو منه،

But the crowd would not expose him, nor favour me so that I could approach him,

Àwọ́n ọ̀gọ̀rọ̀ ènìyàn náà kò ní tú àṣírí rẹ, kò sí lè rọ́rùn fún mí làtí súnmọ́,

فلما تقوضت  الصفوف و أجفل الوقوف،

But when the rows were dispersed, and the bystanders sped off,

Àmọ́ nígbàtí àwọ́n tí wọ́n bẹ̀ lórí ìlà túká, tí àwọ́n tí wọ́n dúró náà tí yáàrá lọ́,

توسمته فإذا هو أبو زيد و الفتى فتاه فعرفت حينئذ مغزاه فيما أتاه،

I marked him, and behold he was Abu zayd, and the boy was his, then I realised his purpose in what he had done,

Mó wá dàmọ̀, ló bá dí Bàbá saídù tí ọ̀dọ́ náà sí jẹ́ ọ̀mọ̀ rẹ̀, nìbáyìí ní mó wá mọ èròngbà rẹ̀ nínú ohùn tí ó ṣe,

و كدت أنقصّ عليه لأستعرف إليه،

And I was nearly falling on him in deliberate to make myself known to him,

Mó fẹ̀ẹ́ ṣú bú lè lórí kí ó bá lè mọ́ ìrú èèyàn tí mó jẹ́,

فزجرني بإيماض طرفه و استوقفني بإيماء كفه،

But he rebuffed me with a glance of his eye, and delayed me with a sign of his hand,

Àmọ́ ó kọ̀ fún mí pẹlú ìyíjú rẹ̀, ó sí tún dàmí dúró pẹ̀lú ìtọ̀ká ọ̀wọ́ rẹ̀,

فلزمت موقفي و أخرت منصرفي،

So I stick to my place, and delayed my departing,

Ní mó bá dúró sí ààyè míì, mó wá lọrá fún lílọ́ míì,

فقال الوالي ما مرامك و لأي سبب مقامك،

And the Governor said: "What is your wish, why are you standing?"

Gómìnà wá béèrè pé: kínní èròngbà rẹ̀, kílódé tí ó fí dúró?"

فابتدره الشيخ و قال إنه أنيسي و صاحب ملبوسي

Quickly the old man interrupted him and said: "He is my friend, and the owner of my clothes,"

Bàbá àgbàlagbà náà wá ṣìwájú rẹ̀ fọ́ èsì pé: dájúdájú ohùn ní ọ̀rẹ́ mí, ohùn ló nì àwọ́n àṣọ̀ míì,

فتسمح عند هذا القول بتأنيسي و رخص في جلوسي،

With this, the Governor was pleased to be friendly with me, and permitted me know have my seat,

Gómìnà wá gbàmí làáyè làtí bámi ṣọ̀rẹ́, ó sì yàn dá kín ń jòkó,

ثم أفاض عليهما خلعتين، ووصلهما بنصاب من العين،

And he made largess to them with a pair of two robes of honour, and presented them with a sum in coin,

Ó wá bùn wọ́n ní ẹ̀bùn àṣọ́ ìró méjì, ó wá tún fún wọ́n ní òwó ní óǹdíwọ̀n góòlù,

واستعهدهما أن يتعاشرا بالمعروف إلى إظلال اليوم المخوف،

And stipulated with them that they should live together in kindness untill the coming of the Day of Fear,

Ọ wá bẹ̀ wọ́n kí wọ́n wúù ìwà dáadáa sí áráwọ́n títí dì àsìkò ọ́jọ́ ìbẹ̀rù,

فنهضا من ناديه مشيدين بشكر أياديه،

Then they rose up from his hall lifting their voices in thanks for his generous hands,

Ní wọ́n bá dìde kúrò nínú gbọ̀gàn ńlá rẹ̀ pẹ̀lú ìdúpẹ̀ fún òòrè ọ̀fẹ́ ọ̀wọ́ rẹ̀,

و تبعتهما لأعرف مثواهما و أتزود من نجواهما،

But I followed them to know their abode, so that I can prepare for myself of their talk,

Mó wá tẹlé wọ̀n kí ń bálè mọ́ ìbùgbè wọ́n, kí tún lè ṣe ànfàní nínú ọ̀rọ̀ wọ́n,

فلما أجزنا حمى الوالي و أفضينا إلى الفضاء الخالي،

But when we have traversed the territory of the Governor, and had come to the empty plain,

Nígbàtí á tí wá kọ̀já kúrò ní àgbègbè Gómìnà, tí á tí wá bọ́sí ìtá gbángba,

أدركني أحد جلاوزته مهيبا بي إلى حوزته،

One of his guards overtook me, recalling me to his court,

Ọ̀kan nínú àwọ́n òlùṣọ́ bá l'epá bá míì, l'ẹ̀ní tí ń pèmí lọ̀ sí yáàrá rẹ̀,

فقلت لأبي زيد ما أظنه استحضرني إلا ليستخبرني،

So I said to Abu zayd: "I think he didn't send for me except to question me,"

Mó wá sọ́ fún bàbá seídù pé: "Mó lérò pé kò ránṣẹ sí míì jù pé ó fẹ̀ ṣe ìwádìí ọ̀rọ̀ lọ̀wọ́ míì,

فماذا أقول و في أي واد معه أجول؟،

Now what shall I say, and in what valley should I roam about with him?

Kínní kín ń sọ́, atí pé nínú àfónìfójì wò ní kín ń mú lọ́?"

فقال بين غباوة قلبه و تلعابي بلبه،

He replied: "Show him the foolishness of his heart, and how I have played with his understanding,"

Ó fọ́ èsì pé: "ṣe àlàyé àágọ̀ rẹ̀ fún, kí ó sì jẹ́ kó mọ̀ bí mó ṣe fí làákàyè rẹ̀ ṣe èré,"

ليعلم أن ريحه لاقت إعصارا و جدوله صادف تيّارا"

So that he can know that his breeze had met whirlwind, and his streamlet had encountered the ripple,

Kí ó bá lè mọ́ pé : àtẹ́gùn rẹ̀ tí pàdé ìjì, ìṣán omí rẹ̀ tí pàdé ìgbì omí,

فقلت أخاف أن يتقد غضبه فيلفحك لهبه،

I siad that his anger might kindled,  so his blaze will scorch you,

Mó fèsì pé èmí ń bẹrù kí ìná ìbínú rẹ̀ máa kò, kí jíjò fèrè ìná náà màá jò ẹ̀,

أو يستشري طيشه فيسري إليك بطشه،

Or that his caprice will quicken, therefore his violence will come upon you,

Tàbí kí ọ̀pọ́lọ́ ète rẹ̀ ó yáàrá ró'rí, tí yíò fí jẹ̀ kí ìbínú rẹ̀ ó gbá ìrẹ́ mú,

فقال إني أرحل الآن إلى الرها و أني يلتقي سهيل و السها،

He said: "I am now traveling to Roha, and how should Sohayl and Suha meet together?"

Ló bá sọ̀ pé: "dájúdájú èmí ń ní ìsin ṣe ìrìn àjò lọ sí Rọ̀há, báwo ní Sòéìlì yíò ṣe pàdé Sùá?"

فلما حضرت الوالي وقد خلا مجلسه و انجلى تعبسه،

Now when I was in the presence of the Governor, whose hall was by this time empty, and whose severity has cleared away,

Nígbàtí mó tí wá dé ọ̀dọ̀ Gómìnà, páàpá gbọ̀ngàn rẹ̀ tí dáa, ìfájúró rẹ̀ sì tí túká,

أخذ يصف أبا زيد و فضله و يذم الدهر له،

He started describing Abu zayd and his worth, and blaming his evil fortune,

Ó wá ń ròyìn Bàbá seídù atí ọ̀lá rẹ̀, tí ó sì tún bú òṣì rẹ̀,

قال أنشدتك الله ألست الذي أعاره الدست فقلت لا و الذي أحلك في هذا الدست،

Then he said : I beseech you by Allah, isn't you who lent him the suit (Dast)?, I said: "No by him who has set you on this cushion (Dast),"

Ó sọ̀rọ̀ pé: Mó bẹ̀ọ́ pẹlú Ọ̀lọ́hùn, ṣe ìwọ́ kọ́ ló yáá ní àṣọ́(Dàsítì) yẹ̀n nìí? Mó fèsì pé: "Rárá èmí kọ́, mó búrà pẹlú Ọlọhùn tí ó gbé ẹ̀yín sí orí àga tìmútìmú Dàsítì),"

ما أنا بصاحب ذلك الدست بل أنت الذي تم عليه الدست.

I am not the owner of the suit (Dast), but you are the one that the game of Dast had came upon,

Èmí kò kì ń ṣe tí ó ní àṣọ́ Dàsítì yẹ̀n, àmọ́ ẹ̀yín ní èèyàn tí ó jẹ̀pé éèré òṣùpá Dàsítì parí lè lórí,

فازورت مقلتاه واحمرت وجنتاه،

Then his eyeballs went askance and his cheeks reddened,

Ẹ́yín ojú rẹ̀ méjèjì yìlọ́ yìbọ̀ ní títí ìkẹ́fín sí míì, ẹ̀kẹ́ẹ̀rẹ̀ méjèjì sí pọ́n wá,

و قال والله ما أعجزني قط فضح مريب و لا تكشف معيب،

And he said, "by Allah it has never baffled me for once to expose a suspicious person, or to discover a flaw,

Ó wá sọ̀ pé, "Mó búrà pẹlú Allah kò jọ̀mí lójú rárá látì tú àṣírí èèyàn tí á bá kẹ́fín sí, kí á sì tún ṣiṣọ́ lójú àlébù,

ولكن ما سمعت بأن شيخا دلس بعدما تطلس و تقلس،

But I have never heard of a Sheik who cheated after he had put on the saintly cloak(scarf and cap),

Àmọ́ èmí kò gbọ́ rí pé, àgbàlagbà kàn ṣe jàmbá lẹyìn tí ó tí wọ́ àṣọ́ ìkọ́rùn àtí fìlà (àṣọ́ òlùbẹ̀rú Ọlọhùn)

فبهذا تم له أن لبس

As for this one, he has deceived to the last,

Ẹ̀ wá rí eléyìí, ó tí ṣe àṣémọ̀ níbí ẹ̀tànjẹ́ báyìí,

أفتدري أين سكع ذلك اللكع؟

Did you know where that rascal was strolling to?,

Ńjẹ̀ ṣe ó mọ̀ ìbí tí olùṣe ìbàjẹ́ yẹ́n rìn lọ́?,

قلت أشفق منك لتعدي طوره فظعن عن بغداد فوره،

I said, "he dreaded you on account of having overstepped his bound, and he journeyed away from Baghdad at once,"

Mó fèsì pé, "Ó bẹrù yín lórí pé ó tí kọ̀ja ààlà rẹ̀, lóba yáàrá ṣe ìrìn àjò kúrò nínú ìlú Bàgìdádi lẹ̀kánnà,

فقال لا قرب الله له نوى و لا كلأه أين ثوى،

He said may Allah not shorten his journey, or keep him where he sojourns,

Ló wá sọ pé, "Ọ̀lọ̀hùn kò ní jẹ̀kí ó tètè de'bí tí ó ń lọ́, kò sì ní ṣọ́ níbí tí ó bá fará pamó sí,

فما زاولت أشد من نكره ولا ذقت أمر من مكره،

For I have never dealt with any violence than his skillful deceit, or tasted more bitter than his fraud,

Torí wìpé èmí kò tí rí ìrú ẹ̀tànjẹ́ tó burú tó tìẹ́ rí, mìò sì tí tọ̀wo ìrú èète rẹ̀ yì rí,

و لولا حرمة أدبه لأوغلت في طلبه، إلى أن يقع في يدي فأوقع به،

And if not for the sacredness of his scholarism, I would have urge to search for him, until he came in sight of me to fall foul of him,

Tì kí bá ṣe ọ̀lá ọ̀wọ̀ tí ń bẹ́ fún mímọ rẹ̀, èmí kò bá bùkáàtà kí ń ṣe ìwádìí rẹ̀, títí yíò fí bọ́ sí míì lọ́wọ́, tí màá fí wá fìyà jẹ,

و إني لأكره أن تشيع فعلته بمدينة السلام فأفتضح بين الأنام،

And now I loathe what he has done to spread across the City of peace, Consequently I may be dishonoured among men,

Dájúdájú èmí kò rírà kí ìwà ìbàjẹ́ rẹ̀ kó fọ̀nká ká kírí ìlú àlàáfíà, tí yíò wá jásì pé má wá dí ẹ̀ní àbuku láàrín àwọ́n èèyàn,

و تحبط مكانتي عند الإمام و أصير ضحكة بين الخاص و العام،

And my dignity would come to nought before the Imam, and I been made a laughing stock between each and everyone,

Kí ipò mí má jàbọ́ lọ̀dọ̀ Lèmámù, tí má fí wá dì èèyàn yẹ̀yẹ́ láàrín àwọ́n èèyàn,

فعاهدني على أن لا أفوه بما اعتمد ما دمت حلا بهذا البلد،

Then he stipulated with me that I should not speak of what Abu zayd had done as long as I remained a sojourner in this city,

Ó wá bẹ̀ míì pé èmí kò gbọdọ̀ sọ̀ ohùn tí Bàbá seídù ṣe níwọ̀n ìgbàtí mó bá ṣì ń bẹ́ nínú ìlú náà,

قال الحارث بن همام فعاهدته معاهدة من لا يتأول ووفيت له كما وفى السموأل،

Said Al-Harith son of Hamam: "I stipulated with him as one who does not equivocate, and I kept promise with him like Samuel had done,

Al-hárìsu ọmọ Hàḿámu sọ̀pé : "Èmí wá bá ṣe àdéhùn gẹgẹ bí èèyàn tí kò ṣì íyè méjì, mó wá pé àdéhùn rẹ̀ gẹgẹ bi Sámùẹ́lì tí pé àdéhùn,

S.A KOLAYO.

2 likes 490

share : whatsapp share


You must be logged in to contribute to discussions here !

No comments found yet for this post