Sodiq Kolayo Translation of the book - maqsuratu ibn dureid (مقصورة ابن دريد) into English and Yoruba languages 03-Aug-2020Translation-of-the-fourth-ten-stanzas-of-Maqsurat-ibn-Dureid(مقصورة-ابن-دريد) alt=

Translation of the fourth-ten stanzas of Maqsurat ibn Dureid(مقصورة ابن دريد)


وَإِن تَكُـن مُدَّتُـهـا مَوصـولَـةًبِالحَتفِ سَلَّطتُ الأُسا عَلى الأَسـى

And if its duration is linked to death, then I have dedicated the condolence of my death to end this suffering.

Tí àwọn àsìkò ìṣòro yìí bálọ́ já sìkú, tóò mó tí fì íkẹ̀dùn ìkú mì tẹlé ìbànújẹ.

إِنَّ اِمرأَ القَيسِ جَرى إِلـى مَـدى فَاِعتاقَـهُ حِمـامُـهُ دونَ الـمَـدى

Certainly Imr-l-Qais ran to accomplish his mission, but his death hindered him from accomplishing it.

Dájúdájú Imr-l-Qais gbìyànjú láti dé ibí èròngbà rẹ, ṣùgbọ́n ìkú rẹ kọ̀ fún láti dé ibẹ̀.

وَخامَرَت نَفسُ أَبي الجَبرِ الجَـوى حَتّى حَواهُ الحَتفُ فيمَن قَد حَـوى

And the soul of Abu al-Jabr was brewed by the illness caused by the suffering until death casted him among whom it had casted.

Ẹ́mì Àbú-l-Jàbr wá rò pápọ̀ mọ́ ìbànújẹ títí ikú fì kò pápọ̀ mọ́ àwọn tó tí pá.

وَاِبنُ الأَشَجِّ القَيـلُ سـاقَ نَفسَـهُ إلى الرَدى حِذارَ إِشمـاتِ العِـدى

And the chieftain who was a son of Ashaj, led himself to destruction, while preventing himself from being mocked by his enemies.

Àtí bàálẹ̀ tó jẹ́ ọmọ àshàj, dárí ẹ̀mí rẹ lọ́ síbí ìpárùn níbí tí ohùn tí ṣọ́ rárẹ́ lọ̀wọ́ ébù ọ́tà.

وَاِختَرَمَ الوَضّاحَ مِـن دونِ الَّتـي أَمَّلَهـا سَيـفُ الحِمـامِ المُنتَضـى

Waddoh was slayed before he could reach his aim by the unsheathed sword of death.

Ìkú ṣẹ́ Wàddọ́h lẹ̀yín dínà éròngbà rẹ̀ pèlú ìdá ìkú tí wọn tí yọ Kúrò nínú akọ.

وَقَد سَما قَبلي يَزيـدٌ طالِباً  شَأوَ العُلى فَما وَهى وَلا وَنـى

Yezid had soared higher seeking for the tower of greatness, he doesn't fail nor weak.

Pápá Yẹ̀zíd tí gàá tí otún ṣé gbìyànjú láti dé ibí gíga, kò kú rẹ tẹ kò sì ṣọ̀ lẹ́.

فَاِعتَرَضَـت دونَ الَّـذي رامَ وَقَـد جَـدَّ بِـهِ الجِـدُّ اللُهَيـمُ الأُرَبـى

Also, he was barred from his aim by a deadly sickness. Besides he had been favoured by his deligence.

Árẹ̀ tín gbẹ̀mí ẹ̀ní ló gùnrín wá bá dìná èròngbà rẹ, pápá ìgbìyànjú rẹ sì tín gbé.

هَل أَنا بِدعٌ مِـن عَرانيـن عُلـى جارَ عَلَيهِم صَرفُ دَهـرٍ وَاِعتَـدى

Am I the first person  among the nobles,  that life will be unjust and assaultive with?

Ǹjẹ́ émi jẹ àkọ́kọ̀ nínú àwọn èyán òní ipò gíga, tí ìgbà ṣe òjóró fún tó tún kọjú ìjà sí?

فَـإِن أَنالَتنـي المَقاديـرُ الَّــذي أَكيـدُهُ لَـم آلُ فـي رَأبِ الـثَـأى

But if destiny favoured me to gain what am craving for, I would not hesitate to reform the damaged.

Tí kádàrá bá ṣe ohùn tí mó ńfẹ̀ ní, mío ní kùnlá lá tí ṣe àtúnṣe ohùn tó tí bájẹ̀.

وَقَد سَمـا عَمـرٌو إِلـى أَوتـارِهِ اِحتَطَّ مِنها كُـلَّ عالـي المُستَمى

In fact Amr has rose his vengeance, and finally pulled down all the eminent people.

Pápá Àmr tí gá dé ípò atí gbẹsán, ló bá sọ̀ gbógbó àwọn tí wọn tí wà lókè ká lẹ̀

4 likes 1,578

share : whatsapp share


You must be logged in to contribute to discussions here !