Sodiq Kolayo Translations of the book - maqamat-al-hareeri into English and Yoruba 05-Oct-2020بواقي-المقامة-الثانية-و-العشرين. alt=

بواقي المقامة الثانية و العشرين.


CONTINUATION OF THE 22ND ASSEMBLY OF HARIRI.

فلما انتهى في الفصل إلى هذا الفصل،

E - Now when, in his judgement, he had arrived at this point,

Y - Nígbàtí ó tí wá dé ibí ìpele yìí, níbí ìdájọ rẹ,

لحظ من لمحات القوم أنه ازدرع حبا و بغضا، و أرضى بعضا و أحفظ بعضا،

E - He saw from the glances of the people that he had sowed love and hatred, and that he he'd pleased a part and angered other.

Y - Nìbáyìí lo wá ṣe àkíyèsí níbí wíwo àwọ́n ìjọ náà pé dájúdájú ohùn tí gbìn ìfẹ àti ìkórìrá , ohùn sì tí wá ìyọnú àpákàn atí ìbínú àpá míràn.

فعقب كلامه ، بأن قال: إلا أن صناعة الحساب موضوعة على التحقيق، و صناعة الإنشاء مبنية على التلفيق،

E - So he followed up his discourse by saying: Except that the art of Account is based on verification, and the art of Composing is structured on fabrication.

Y - l'oba fí tẹlé ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé dájúdájú ọ̀nọ̀ ìṣírò ohún tí wọn gbé kàlẹ lerí ìjẹ́rìsí nìí, bẹẹ náà ní ọ̀nọ̀ àròsọ òhún tí wọn mọ́ọ̀ lerí ìrọ́ nìí,

و قلم الحاسب ضابط و قلم المنشئ خابط.

E - And the pen of the accountant holds firm, but the pen of the composer stumbles.

Y - Gègé olùṣe ìṣirò á má dúró ṣinṣin, ṣùgbọ́n gègé àláròsọ́ á má ṣubú.

وبين إتاوة توظيف المعاملات ، وتلاوة طوامير السجلات ،

E - And between the taking of tribute by the impost on transactions, and the reading of the leaves of registers,

Y - Láàrìn gbígba owó òranyàn níbí ìbarà ẹní ṣe, atí kìká àwọ́n ìwé ìfórùkọ́sílẹ̀,

بون لا يدركه قياس و لا يعتوره التباس.

E - There is a difference to which comparison can not apply, into which doubt cannot enter.

Y - Ni ìyátọ̀ ǹbẹ́ tí àfiwé kán kò lé bá a, bẹẹ sì ní ìyè méjì kàn kò lé sá wọ́ọ̀.

إذ الإتاوة تملأ الأكياس، و التلاوة تفرغ الرأس،

E - Because tribute fills purses, but reading empties the head,

Y - Nìtórí wìpé gbígba owó á má kún àwọ́n àpò, àmọ́ kíkà ìwé a má sọ òrí dí òfìfó,

و خراج الأوارج يغني الناظر و استخراج المدارج يعني الناظر،

E - And the tax of the memorandum-book enriches the overseer, while the interpretation of the rolls wearies the eyes,

Y- Bẹ̀ẹ́ sì ní ìwé sìsán òwó orí  á má kó ọ́rọ̀ bá àlámojútó rẹ, tí ìtúpalẹ̀ àwọ́n ìlá ìwé a má kúrẹ̀tẹ̀ ojú òlùkàwé.

ثم إن الحسبة حفظة الأموال، و حملة الأثقال، و النقلة الأثبات و السفرة الثقات،

E - And then also the Accountants are the guardians of wealth, the bearers of burdens, the truthful relators, the trustworthy envoys,

Y - L'ẹ̀hin náà dájúdájú àwọ́n òlùṣírò owo ní olùṣọ àwọ́n dúkìá, olùgbé àwọ́n bùkáàtà, olùgbẹ̀gbàwá tí wọn jẹ olóòótọ, àṣòjú tí alè gbára lé,

و أعلام الإنصاف و الانتصاف، و الشهود المقانع في الاختلاف،

E - the guides in doing justice and obtaining it, the sufficing witnesses in the breach of argument,

Y - àwọ́n ní òní déédé atí tí wọ́n sì ń ṣe déédé fún ẹ́lòmíràn, ólùjẹ̀rí tí àwọ́n èèyàn a má gbá tító pẹlú wọn níbí àríyànjiyàn,

و منهم المستوفي الذي هو يد السلطان و قطب الديوان،

E - And among them is the Minister of Finance who is the Hand of the King, and the Pivot of the Council,

Y - Nínú wọ́n ní ìránṣẹ́ òní déédé fún ìṣúná tí ó sì jẹ́ olùrànlọ́wọ́ Ọ̀bá,

و قسطاس الأعمال و المهيمن على العمال،

E - the Balance of business, and the overseer of the agents.

Y - Pẹ̀rẹ̀gí àwọ́n ìṣòwò atí àlámojútó àwọ́n òṣìṣẹ́,

و إليه المآب في السلم و الهرج، و عليه المدار في الدخل و الخرج،

E - To him is the reference in peace and war, on him is the management in revenue and expenditure,

Y - Ọ̀dọ̀ rẹ ní ìdarí sí lásìkò àlàáfíà atí àsìkò ògùn, orí rẹ ní ètò èrè ati ìnáwó má ń yí lé,

و به مناط الضر و النفع و في يده رباط الإعطاء و المنع.

E - by him hang the disadvantage and advantage, and in his hand is the rein of giving and denying,

Y - Orí rẹ ní wọ́n fí ìnírá atí ànfàní kọ̀ sí, ìnú ọwọ rẹ ní ìdè ìtọ́rẹ́ atí ìṣàhún ń bẹ́.

و لولا قلم الحسّاب لأودت ثمرة الاكتساب، و لاتّصل التغابن إلى يوم الحساب،

E - And if not for the pen of the Accountants, the fruit of earning would have perished, and fraud would have endure till the Day of Judgement.

Y - Tíkì bá ṣe tí gègé àwọ́n òlùṣírò ní, èsó èrè kò bá tí párún, ìwà jìbìtì kò bá wà bẹ́ dì ọjọ ìṣirò.

و لكان نظام المعاملات محلولا و جرح الظلامات مطلولا،

E - the order of transactions would have been loosened, the wounds of wrongs would be unavenged,

Y - ètò ìbarà ẹní ṣe kò bá tí tú, ọ̀gbẹ́ àwọ́n àbósí kò bá tí dì òun tí á kò lè gbẹsán rẹ,

و جيد التناصف مغلولا و سيف التظالم مسلولا،

E- The neck of just-dealing would be fettered, and the sword of wrong-dealing be drawn,

Y- ọ́rùn ìṣe dédé tí dì òun tí wọn dè ní ṣẹ̀kẹ́ṣẹ́kẹ̀, tí ìdá áìkò ṣe dédé tí dì òun yọ́ jáde.

على أن يراع الإنشاء متقوّل، و يراع الحساب متأول

E-. Moreover the pen of composition fables, but the pen of accounting interprets,

Y- Pẹlú pé dájúdájú gègé àròsọ á má pá'rọ̀ ṣùgbọ́n gègé ìṣìrò á má sọ òtítọ,

و المحاسب مناقش و المنشئ أبو براقش،

E- And the Accountant is a close scrutinizer, while the Composer is Abu Barakish,

Y- Òlùṣírò jẹ olùyẹ̀wò tí Àláròsọ́ sì jẹ Àbú-Bàrákíṣì,

و لكليهما حمة حين يرقى إلى أن يلقى و يرقى،

E- Yet each, when he rises high, has his venom until he been met and charmed,

Y- Àmọ́ ikinni keji wọn, tí ó bá gá lọ́ s'oke, ní òró títí ó fí ṣe alábá pàdé tí wọn yíò sì sà síì.

و إعنات فيما ينشى حتى يغشى و يرشى،

E- And in what each produces there is misery until he will be visited and bribed,

Y- Ìnírá ń bẹ̀ nínú òun tí ìkíni kejì wọ̀n kọ̀ títí dì ìgbà tí yíò fí ṣe àbẹwò sí tí wọn yíò sì fún ní owó abẹ̀tẹ́lẹ,

إلا الذين آمنوا و عملوا الصالحات و قليل ما هم.

E- Except those that believe in Allah and do righteousness,- And little they are in number!

Y- Àyáfí awọn tí wọn nígbàgbọ́ tí wọ́n sì tún ṣe àwọ́n ìṣẹ́ rére , ṣùgbọ́n diẹ ní óǹkà wọn.

قال الحارث بن همام : فلما أمتع الاستماع بما راق و راع،

E- Said Al-Harith son of Hamam: Now when he has thus supplied our hearings with what was pure and good,

Y- Al-Hárìs Ọmọ Hàḿámu sọ̀pé: Nígbàtí ó tí wá fún etì wá ní òun tí ó rẹwà tí ó sí dára,

استنسبناه فاستراب و أبى الانتساب، و لو وجد منسابا لانساب،

E- We asked him of his lineage, but he was suspicious, and refused to say it, and if he had found a place to escape he would have escaped,!

Y- À wá bìí ní ìbéèrè nípa ìran rẹ, lóba ńkẹ̀ fín, tí ó sì tún kọ̀ láti júwe rẹ, kódà bí ó bá rí ìbùsàlọ́ kò bá sàlọ́,

فحصلت من لبسه على غمة حتى ادّكرت بعد أمة،

E- Then from his secrecy I was in sorrow, then after awhile I remembered him,

Y- Nì mó bá wà nínú ìbànújẹ níbí ìrújú rẹ, títí mó fí rántí rẹ,

فقلت : والذي سخر الفلك الدوّار و الفلك السيّار، إني لأجد ريح أبي زيد، و إن كنت أعهده ذا رواء و أيد،

E- And I said: Now by Him who controls the rolling heaving and the voyaging ships, surely I am catching the scent of Abu zayd, though once I knew him as the Lord of attractiveness and vigour,

Y- Mò sọ̀pe : Mó búrà pẹlú Ẹ̀ní tí ó sẹ̀ ọ̀rún tí ńyí rọ̀ atí ọ̀kọ̀ ojú omí tí ńrìn rọ̀, dájúdájú èmí ń gbọ́ òrun Àbú seídù, bíò tí ẹ̀ jàsípe nígbà kán rí ó jẹ èèyàn tí ó rẹ̀wà tí ó sí tún sàngùn,

فتبسم ضاحكا من قولي ، و قال : أنا هو على استحالة حالي و حولي،

E- And He smiled, laughing at my speech and said, "I am he, though with a change in state and strength,

Y- L'òbá rẹ̀rìn mùsẹ́, l'ẹ̀ni tí ń fẹ̀yín sí ọ̀rọ̀ mí, ó wá fèsì pé, "Èmí náà ní onítọ̀hún, ṣùgbọ́n ìṣe sí mí atí agbára mí tí yípadà,

فقلت لأصحابي ,: هذا الذي لا يفرى فريّه و لا يبارى غبقريّه،

E- Whereupon I said to my companions, "after whose fashioning none can fashion, whose spite is not to be vied with,"

Y- Nìmó wá sọ̀ fún àwọ́n ọ̀rẹ́ mí pé, "eléyìí ní ẹní tó ṣé pé èèyàn kánkán kólé mú irú àrà rẹ wá, tí wọn sì kólè fígà gbágà níbí ìdíje,

فخطبوا منه الود و بذلوا له الوجد،

E- Then they courted his friendship and offered him wealth,

Y- Lẹyìn náà ní wọ́n bá ṣọ̀rẹ́, tí wọ́n sì tún náà owó fún,

فرغب عن الألفة و لم يرغب في التحفة،

E- But he declined from intimacy, and leaned not to the gift,

Y- Ṣùgbọ́n ó kọ̀ láti bàwọ́n ṣọ̀rẹ́, kò sí tún rókàn sí ẹ̀bùn wọ́n,

و قال : أما بعد أن سحقتم حقي، لأجل سحقي، و كسفتم بالي لإخلاق سربالي،

E- And he said, "since you have hurt my honour because of my worn garment, and casted a shadow on my soul for the threadbareness,"

Y- O tún wá sọ pé, "nìbáyìí tí ẹ̀ tí wọ́ ìyí mí nílẹ̀ nítorí àṣọ̀ mí totí ṣá, tí ẹ̀ sí tún kọ̀dí ẹ̀mí mí nítorí àṣọ̀ yìyá mí,

فما أراكم إلا بالعين السخينة و لا لكم مني إلا صحبة السفينة ، ثم أنشد :

E- I will look upon you only with a heated eye, you shall have from me only a ship's companionship," then he chanted:

Y- Èmí a má ṣọ̀yín àmọ́ pẹlú ojú gbóná ní, èmí kò sí ní báyìn ṣe jú ìbáṣepọ̀ orí ọ̀kọ̀ ojú omí lọ́," l'ẹ̀hìn náà ló wá kọ̀rin pé:

اسمع أخي وصية من ناصح

ما شاب محض النصح منه بغشه

E- Hear, my brother, commandment from a counselor who mixes not the purity of his counsel with deceit,

Y- Gbọ, ìwọ́ ọ̀mọ̀yá mí, àsọ́tẹ́lẹ̀ kán láti ọdọ òníṣítí tí kò ní dá mímọ́ ìṣítí pàpọ mọ́ ẹ̀tàn,

لا تعجلن بقضية مبتوتة

في مدح من لم تبله أو خدشه

E- Hasten not with a decisive judgement in the praise of him, whom you have not tried, nor it the rebuke of him,

Y- Mà ṣe yàrá sí ìdájọ ẹ̀tànjẹ́ kán níbí yíyin tàbí b'ebú èèyàn tí ó ṣe pé ìrẹ́ kò ti gbìdánwò rẹ̀,

وقف القضية فيه حتى تجتلي

وصفيه في حالي رضاه و بطشه

E- But hold your judgement on him untill you have had a view of his two characters in his two conditions of content and anger,

Y- Ṣe sùúrù pẹlú ìdájọ rẹ títí ìwà méjì rẹ̀ yíò fi hàn sí ní ìgbà tí ó bá yọ̀nù àti ìgbà tí ó bá bínú,

و يبين خلب برقه من صدقه

للشائمين ووبله من طشه

E- Until his deceiving flash be distinguished from his truthful one by those who watch it, and his flood from its light rain,

Y- Tí ẹ̀tànjẹ́ mọ̀námọ̀ná rẹ̀ yíò yàs'ọ́tọ̀ kúrò níbí òtítọ rẹ̀ fún gbógbó àwọ́n tí wọn ń wòó, atí àkúnwọsílẹ rẹ̀ kúrò níbí òjò wẹ̀lìwẹ̀lì rẹ̀,

فهناك إن تر ما يشين فواره

كرما و إن تر ما يزين فأفشه

E- And then if you perceive what dishonours him hide it generously, but if you see what becomes him, publish it.

Y- Tí ó bá rí òun tí o tàbùkù rẹ, bó l'àṣírí pẹlú àpónlé, tí ó bá sì rí òun tí ó kó ẹ̀ṣọ́ bá, kède rẹ,

و من استحق الارتقاء فرقه

ومن استحط فحطه في حشّه

E- And whoso deserves to be exalted, exalt him, and whoso deserves to be abase, abase him to the sewer,

Y- Ẹni tí ó bá l'ẹ̀tọ́ sí àgbégá, gbé gá, ẹní tí ó bá sì l'ẹ̀tọ́ sí ìṣubú, gbé ṣùbú sìnú pọ̀tí rẹ,

واعلم بأن التبر في عرق الثرى

خاف إلى أن يستشار بنبشه

E- And know that the pure gold in the vein of the earth is hidden until it is brought out by digging,

Y- Wá lọ́mọ̀ pé gàárà góòlù nínú ìsàlẹ̀ ìlẹ̀, òun tí ó pàmọ́ ní títí dì ìgbà tí wọn yíò fí gbé jáde nínú àyè rẹ,

و فضيلة الدينار يظهر سرها

من حكه لا من ملاحة نقشه

E- And the worth of Debar, its secret appears by scratching it, not from the beauty of the graving,

Y- ìyì Dìnárù, àṣírí rẹ á má jáde láti ibì hìhọ́ rẹ̀, tí kì ṣe látí ìbì ẹwà gbígbẹ rẹ̀,

ومن الغباوة أن تعظم جاهلا

لصقال ملبسه و رونق رقشه

E- It is a foolishness for you to magnify the ignorant, because of the brightness of his dress and the splendour of his adorning,

Y- Nínú àgọ ní kí ó má gbé àpónlé fún òmùgọ nítorí àṣọ́ rẹ atí dídá ẹ̀ṣọ́ rẹ̀,

أو أن تهين مهذبا في نفسه

لدروس بزته و رثة فرشه

E- Or you should belittle a man that is refined in soul because of the threadbareness of his garb and the shabbiness of his furniture,

Y- Tàbí kí ó lọ́ yẹpẹrẹ ẹ̀lẹ̀ẹ́kọ́ nítorí àṣọ́ gbìgbó rẹ tàbí ṣìṣá àwọ́n ẹ̀ṣọ́ ilé rẹ,

ولكم أخي طمرين هيب لفضله

و مفوف البردين عيب لفحشه

E- For how many an owner of two torn mantles is reverenced for his worth, and he that is stripped is ill-fame through his baseness,

Y- mèlò mèlò ẹ̀ní tí ó ní àṣọ́ gbìgbó méjì tí wọn sì pọ̀nlé nítorí mímọ rẹ, bẹ sìní aláṣọ ọ̀lá-méjì òlókùn fúnfún tí ó sí kán àbùkù nítorí isọkusọ rẹ,

و إذا الفتى لم يغش عارا لم تكن

أسماله إلا مراقي عرشه

E- If a man approaches not to obscenity, then his rags are only steps to his throne,

Y- Tí ọ̀dọ̀mọ́kùnrín kò bá tí wúwà àìbìkítà/ láìfí, àwọ́n èkísà ará rẹ kò jẹ nkán kán jú atẹgun débi àga ọ̀là rẹ lọ́,

ما إن يضر العضب كون قرابه

خلقا و لا البازي حقارة عشه

E- It hurt not the sword that its sheath been worn, nor the hawk that its nest been mean,

Y- yìyá àakọ̀ ìdà kò lè kó ìpalára bá ìdá, bẹ náà ní ṣìṣá ilé ẹ̀yẹ̀ àṣá kò lè kó ìpalára bá àṣá,

ثم ما عتم أن استوقف الملاح و صعد في السفينة و ساح،

E- Then he delayed not to bid the Sailors to stop, and ascended from the boat and went,

Y- L'ẹ̀hin náà kò lọ̀rá rárá látì dà àtúkọ̀ dúró, ó wá gún ke láti bọ́lẹ̀, ó sí lọ́,

فندم كل منا على ما فرط في ذاته، و أغضى جفنه على قذاته،

E- But each of us repented in what he have been incautious towards him, and drooped his eyelid over his mote,

Y- Ṣùgbọ́n kowá wá ṣe àbámọ̀ kúrò níbí òun tí á ń fí kẹ̀fìn sí pàápàá rẹ̀, Kowa náà sí rẹ̀ ojú rẹ nìlẹ kúrò ìlẹ̀bọ́ ojú rẹ̀,

و تعاهدنا على أن لا نحتقر شخصا لرثاثة برده و أن لا نزدري سيفا مخبوء في غمده.

E- And we vowed that we will never slight a man for his raggedness  his garment, that we would not despise the sword while hidden in the sheath.

Y- À wá ṣe ìlérí pé à kò ní yẹpẹrẹ èèyàn kán kán mọ́ nítorí àkísà rẹ, à kò sí tún ní fojú renà ìdá tí wọn sì tọjú sìnú àkọ̀ rẹ.

S.A KOLAYO

Read more

©️www.qatru.com

2 likes 98

share : whatsapp share


You must be logged in to contribute to discussions here !

No comments found yet for this post