Yoruba:Emi o si mu oti (elerin dodo) ri, Gege biwo se muu titi ti o fi n hunrira.
69. Eng: While I did not grow up in era of advantage,, Butyou did grow up in it and yet did not take the advantage.
Yoruba: Mi o dagba ni asiko ti anfaani wa, Iwo si dagba ninu asiko anfaani sugbon oo se anfaani.
70. Eng: While I did not say in a place where there was
oppression, But you did stay in it and even
trespassed.
Yoruba: Mi o si kosinu re ogba abosi, O sin fa ogba Olohun ya
71. Eng: You have actually associated with great eminent personalities, But I do not see you emulate those you have associated with.
Yoruba: Paapaa o ti ba a won onimimo se tiwon je agbalagba, Mi o si ri e ni eniti o n kose awon eniti o ba se.
72. Eng: The book (Al-Quran) has called on you but you did not answer, And the grey hair has called your attention but you did not heed.
Yoruba: Al-qur'an n pe o sugbon oo da lohun