وقفة
9. الباب الثالث · page 86 / 31
It is not as you think or believe
Yoruba: Ma se ja oro mi yii niyan nitori oro ododo leyii opo, Kii se bi o se roo si rara.
88. Eng: Abubakar, you have disclosed the least of my faults, But (unfortunately) you have concealed most of them.
Yoruba: Mope iwo abubakari kekere ninu laifi mi lo n so, Eyi to poju ninu re ati gbankogbi re lon be lara re ti on pa mo
89. Eng: Say whatever shameful things you want about me, And even if you redouble them you have said the truth.
Yoruba: Ohun ti oba wun e ni ki oi simi lara ninun oro yeye, Tunse adipele re, odo loso oparo
90. Eng: No matter how much you criticize me (I know) it is because of the laxity, Within myself, it is just as if you have praise me
Yoruba: Mase yonu si elekebu se awon eniyan mo nitori laifi Nla ni tin ma jogun wipe ki eniti o nife eniyan ma nife re mo.
91. Eng: Do not tolerate fault-finding because it is actually, A big disgrace that leads the beloved one to hatred.

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru