NUMBERING OF LINE AND THE POEM
IBODI (PIPARI ORIN)
114. Eng: I have completed it (the advice) with nine good pieces, But it was formerly of one hundred and six (pieces).
Yoruba: Paapa moti pari orin mi yii pelu ese orin mesan kan toda, To jepe ese ogorun ati mefa ti saju re.
Blessing for the prophet
115. Eng: : And grant peace my lord to the seal of messengers, As well his noble descendants as you are mentioned.
Yoruba: Olohun ba wa ke ipekun awon ojise (Anobi muhammad) Ati awon molebi re alaponle lopin igba ti won ba n daruko iwo Olohun.