Translations of the book - maqamat-al-hareeri into English and Yoruba English and Yoruba translations of the book - maqamat-al-hareeri are been posted and discussed here
This page was created by : yusuf oyeniyi 30 followers 5,881 views Page Contents

You are not currently eligible to contribute to this page


Sodiq Kolayo 04-Feb-2020

Maqamat Elekeji toje titi ilu hulwan 3


لخصائص آدابه

Tori awon esa eko Toni

و نافست في مصافاته

Mowa gbiyan ju lati ba sore

لنفائس صفاته

Nítorí ojúlówó ìròyìn rẹ

فكنت به أجلو همومي

Mo wà pẹlú rẹ lẹni tin fí ìṣípáyá sí àwọn ìṣòro mí

و أجتلي زماني

Lẹni tin tan imọlẹ sí ìgbà mí

طلق الوجه

Lẹni tin dúnú

ملتمع الضيا

Ti ímólẹ̀ ntan lojumi

أرى قربه قربى

Mori kín sun mo gege bi mọlẹbi

و مغناه غنية

Oro nbe nibi tito pẹlu

و رؤيته ريا

Rírí rẹ irengbe ni

و محياه لي حيا

Esusu jo ni isemi re jẹ fún mi

2 likes 105


Sodiq Kolayo 04-Feb-2020

Maqamat Elekeji toje titi ilu hulwan 2


و آداب بارعة

Ati awon eko totayo

و قدم لأعلام العلوم فارعة

Eni ti ese es bowa ju Ni ninu orisirisi mimo

فكان لمحاسن آلاته

Nitori ewa irinse mimo toni

يلبس على علاته

Ni won se man kaju kuro nibi awon asise re

و لسعة روايته

Ati pe nitori apoju egbawa re

يصبى إلى رؤيته

Niwon se man jeran lati ri

و لخلابة عارضته

Nitori ijoniloju tin be nibi iyara fesi re

يرغب عن معارضته

Ni awon eniyan se man kaju kuro nibi itako

و لعذوبة إيراده

Nitori adun tin be nibi orore

يسعف بمراده

Ni won se man kaju kuro nibi erongba re

فتعلقت بأهدابه

Nimo ba so aso mimo tie

لخصائص آدابه

Tori awon esa eko Toni

و نافست في مصافاته

Mowa gbiyan ju lati ba sore

لنفائس صفاته

Nítorí ojúlówó ìròyìn rẹ

فكنت به أجلو همومي

Mo wà pẹlú rẹ lẹni tin fí ìṣípáy

  ... Read more

2 likes 139


Sodiq Kolayo 03-Feb-2020

Maqamat Elekeji toje titi ilu hulwan 1


المقامةالثانية الحلوانية :

Maqamat Elekeji toje titi ilu hulwan

حكى الحارث بن همام قال

Haris omo Hamam gba egbawa oro , osope

كلفت مذ ميطت عني التمائم

Moyofe lati gba tiwon titu paro kuro lorunmi

و نيطت بي العمائم

Tiwon wa we lawani simi lorun

بأن أغشى معان الأدب

Moni Fe lati malosi awon aye eko

و أنضي إليه ركاب الطلب

Kin wa mawo awon rakun mi mi losibe

لأعلق منه بما يكون لي زينة بين الأنام

Kin bale ri ohun ti yio semi leso laarin aye

و مزنة عند الأوام

Ati ohun ti yio je ojo lasiko ongbe

و كنت لفرط اللهج باقتباسه

Nitori apoju ife ti mo nisi mimo

و الطمع في تقمص لباسه

Ati ojukokoro gbigbe aso mimo wo

أباحث كل من جل و قل

Mon se iwadi lowo gbogbo onimimo nla ati kekere

و أستسقي الوبل و الطل

Mon wa wa omimu lowo agbanla Ojo a

  ... Read more

1 like 158


yusuf olalekan 30-Dec-2019

Titu muqadima Makama alfa hariri si ede abinibi 2


و بعد

Leyin naa

فإنه جرى ببعض أندية الأدب

Dajudaju , awon oro kan nlo nbo ninu awon  gbogan eko litiraso

الذي ركدت في العصر ريحه

Eyi to sepe fife ategun eko naa ti sile lasiko yii

ذكر المقامات

Oro naa ni iranti makamat

التي ابتدعها بديع الزمان

To sepe badi'u zaman lo bere re

و علامة همذان

Oni mimo repete loje ninu ilu Hamazan ni Iraq

و عزا إلى أبي الفتح الأسكندري نشأتها

Ose afiti hihun oro makamat sodo Abu-l-fatih ara Ilu askandar

و إلى عيسى بن هشام روايتها

Osi se egbawa makamat so I'sa omo hisham

كلاهما مجهول لا يعرف

Ikini keji won je eniti ako mo

و نكرة لا تتعرف

Ajoji ni won tio si eni tomo won

فأشار من إشارته حكم

Eniti itoka reje ofin ba toka

و طاعته غنم

Ti oro(ere) nbe ninu titele itoka naa

إلى أن أنشئ مقامات

Ti mo fi wa bere

  ... Read more

3 likes 153


yusuf olalekan 23-Dec-2019

Titu muqadima Makama alfa hariri si ede abinibi


اللهم إنا نحمدك على ما علمت من البيان و ألهمت من التبيان

Olohun wa o, dajudaju awa ndupe fun o lori mimo alaye oro tofi mowa ati lori inuni ni mimo agboye .

كما نحمدك على ما أسبغت من العطاء و أسبلت من الغطاء

Gegebe naa lan seyin fun o lori eyi to dabo wa ninu awon ore nta , ati eyi to fi dabo wa ninu awon abo kuro ninu aburu

و نعوذ بك من شرة اللسن و فضول الهذر

Awa nwa iso pelu abo re olohun kuro ninu isokuso eri ahon ati kuro ninu asadanu oro tiko ni anfani.

كما نعوذ بك من معرة اللكن و فضوح الحصر

Bakana lanwa o loluso kuro laifi ikalolo ati ibaje kikulenu

ونستكفي بك الافتنان بإطراء المادح و إغضاء المسامح

Awa iso pelu gbigba Tito pelu re kuro nibi kiko airoju barawa fun etanje alayin boro ati kuro nibi aburu ikaju olu paniti tiki tuni SE

كما نستكفي بك الانتصاب لإ

  ... Read more

3 likes 2 217