Translations of the book - maqamat-al-hareeri into English and Yoruba English and Yoruba translations of the book - maqamat-al-hareeri are been posted and discussed here
This page was created by : yusuf oyeniyi 30 followers 6,553 views Page Contents

You are not currently eligible to contribute to this page


Sodiq Kolayo 05-Oct-2020

بواقيالمقامةالثانيةوالعشرين.

بواقي المقامة الثانية و العشرين.


CONTINUATION OF THE 22ND ASSEMBLY OF HARIRI.

فلما انتهى في الفصل إلى هذا الفصل،

E - Now when, in his judgement, he had arrived at this point,

Y - Nígbàtí ó tí wá dé ibí ìpele yìí, níbí ìdájọ rẹ,

لحظ من لمحات القوم أنه ازدرع حبا و بغضا، و أرضى بعضا و أحفظ بعضا،

E - He saw from the glances of the people that he had sowed love and hatred, and that he he'd pleased a part and angered other.

Y - Nìbáyìí lo wá ṣe àkíyèsí níbí wíwo àwọ́n ìjọ náà pé dájúdájú ohùn tí gbìn ìfẹ àti ìkórìrá , ohùn sì tí wá ìyọnú àpákàn atí ìbínú àpá míràn.

فعقب كلامه ، بأن قال: إلا أن صناعة الحساب موضوعة على التحقيق، و صناعة الإنشاء مبنية على التلفيق،

E - So he followed up his discourse by saying: Except that the art of Account is based on verification, and the art of Compo

  ... Read more

2 likes 272


Sodiq Kolayo 28-Aug-2020

THETWENTYSECONDASSEMBLYOFHARIRI

THE TWENTY SECOND ASSEMBLY OF HARIRI


المقامة الثانية و العشرون

THE 22ND ASSEMBLY OF HARIRI

الفراتية

OF THE EUPHRATES

حكى الحارث بن همام قال أويت في بعض الفترات إلى سقي الفرات،

Al-Harith son of Hamam related : I ranged myself during the time of quiet, to the water-lands of the Euphrates,

Hárìth ọ̀mọ̀ Àḿám̀ù gbá ẹ̀gbàwá ọ̀rọ̀ pé: "Mó dàmùrè, ní àpákàn àwọ́n àsìkò ìsínmí, lọ́ sí ààyè ìbómírín Òdò Fùrátì,

فلقيت بها كتابا أبرع من بني الفرات و أعذب أخلاقا من الماء الفرات

And there I met with writers, more excellent than the sons of Al-Furat, more pleasant in manners than the sweet water,

Mó wá pàdé níbẹ̀, àwọ́n òlùkọ̀wé tí wọ́n perégedé jú àwọ́n ọ̀mọ̀ Fùrátì lọ́, tí ìwà wọ́n sì dùn jú òmí àdùn lọ́,

فأطفت بهم لتهذبهم لا لذهبهم و كاثرتهم لأ

  ... Read more

4 likes 208


Sodiq Kolayo 26-Aug-2020

CONTINUATIONOFTHE23RDASSEMBLYOFHARIRI

CONTINUATION OF THE 23RD ASSEMBLY OF HARIRI


قال فبرز الشيخ مجليا و تلاه الفتى مصلّيا،

-Then started forth the old man as the winning horse, while the boy followed him like the second in the course,

Bàbá àgbàlagbà náà wá jáde sí ìtá gẹgẹ bí ẹ̀ṣìn tí ó ṣàjú, tí ọ̀dọ́(ọ̀mọ̀) náà sì tẹlé gẹgẹ bí ẹ̀ní Kejì níbí ìdíje,

و تجاريا بيتا فبيتا على هذا النسق إلى أن كمل نظم الأبيات واتسق:

And they both raced together stanza by stanza in this order, until the series of stanzas was perfected and made up:

Wọ́n jọ̀ wá ń fì ẹ̀sẹ̀ órín kán kán jágbà láàrín àráwọ̀n lórí ìlànà yìí, títí ẹ̀sẹ̀ órín náà fíì pèé, tí ó sí dáàrà:

وهي

وأحوى حوى رقّي برقة ثغره

و غادرني إلف السهاد بغدره

Old Man: There is a ruddy lipped one who has compassed my enslaving with the delicacy of her utterance, and left

  ... Read more

2 likes 284


Sodiq Kolayo 14-Aug-2020

المقامةالثالثةوالعشرون

المقامة الثالثة و العشرون


23rd ASSEMBLY OF HARIRI IN ENGLISH AND YORUBA.

المقامة الثالثة و العشرون: الشعرية

THE 23rd ASSEMBLY OF HARIRI:

"OF THE POETRY".

حكى الحارث بن همام قال: نبا بي مألف الوطن ، في شرخ الزمن ، لخطب خشي ، و خوف غشي،

Al-Harith son of Hamam related: My desire for home was distanced in the prime of my time, through a fearful catastrophe, and through a phobia that came upon me,

Al-Hárìth ọmọ Hàḿámu sọ pé: ìfẹ́ ìlé dí ohùn ìjìnà lásìkò èwé mí, nítorí wàhálà tín dẹ̀rù bánì, atí àyà jíjá tí ó bó mí dàrú,

فأرقت كأس الكرى ، و نصصت ركاب السرى

And I discharged the cup of sleepiness, and I put to their routes the camels of the night journey.

Mó dà òmí tí ó wà nínú ìfé ìtóǹgbé nù, mó wá gbé àwọn ràkúnmí ìrìn àjò òrú sọ̀nà,

و جبت في سيري وعورا لم تدمّثها ا

  ... Read more

1 like 242


Sodiq Kolayo 11-Aug-2020

المقامةالرابعةوالعشرون:القطيعية

المقامة الرابعة و العشرون: القطيعية


THE 24th ASSEMBLY OF HARIRI IN ENGLISH AND YORUBA.

المقامة الرابعة و العشرون : القطيعية

THE TWENTY FOURTH ASSEMBLY:

"THE PORTION".

حكى الحارث بن همام قال: عَاشَرتُ بِقَطِيعَةِ الرَّبِيعِ، في إِبَّانِ الرَّبِيعِ

Al-Harith, son of Hamam related: I was in company in the portion of Ar-Rabî, in the season of spring,

Al-Hárìth ọmọ Hàḿámu gbáà ẹ̀gbáwà ọ̀rọ̀ pé: mó kẹ́gbẹ́ ní ìpínlẹ̀ Ràbî, ní ìgbà òjò,

فِتيَةً وُجُوهُهُم أَبلَجُ مِن أَنْوَارِهِ و أَخْلَاقُهُم أَبهَجُ مِن أزْهَارِهِ، أَلفَاظُهُم أَرقُّ مِن نَّسِيمِ أَسحَارِهِ،

With youths whose faces where brighter than its lights, whose behaviours were more radiant than its flowers, whose utterances were more delicate than the air of its dawns,

Pẹ̀lú àwọn ọ̀d

  ... Read more

2 likes 1 340


Sodiq Kolayo 09-Aug-2020

TRANSLATIONOFTHETWENTYFIFTHASSEMBLYOFHARIRI

TRANSLATION OF THE TWENTY FIFTH ASSEMBLY OF HARIRI


المقامة الخامسة و العشرون : الكرجية

THE TWENTY FIFTH ASSEMBLY CALLED; " OF THE LAND OF KARAJ".

MÀKÁMÀT TÍ Ó WÀ NÍ ÌPÉLÉ MẸ̀Ẹ́DỌ̀GBỌ̀N TÍ WỌN PÉ NÍ; "TÍTÍ ÌLÚ KARAJ".

حكى الحارث بن همام قال : شَتَوتُ بِالكَرَجِ لِدَينٍ أقْتَضِيهِ و أَرَبٍ أقضِيهِ.

Al-Harith son of Hamam, related:

I was wintering at Karaj, by reason of a debt that I was demanding, and a needful business I was doing.

Al-Hárìth ọmọ Hàḿámu gbáà ẹ̀gbáwà ọ̀rọ̀ pé: ọ́yẹ̀ múmì mọ́ ìlú Kárájì, torí gbèsè tí mófẹ̀ gbà, atí torí òwò ìṣẹ́ tí mó ń ṣe.

فَبَلَوتُ مِن شِتَائِها الكَالِحِ و صرِّها النَّافِحِ.

And I experienced of its fierce winter and its scorching cold.

Mòwá fárá dá ọ́yẹ̀ rẹ̀ tí ó lágbára atí òtútù rẹ̀ tí ó pọ́.

ما عَرّفَ

  ... Read more

2 likes 1 451