5. Eng: (I can't imagine) how much you get deceive, But for how long will you continue without leaving her?
Yoruba:Igba wo ni waa gba etanje lara aye da, titi di igba Wo gan? Titi digba wo? se oo ni gunri kuro nibi aye yii ni? titi digba wo?
Significance of knowledge and its Beauty
PATAKI ATI OLA TINBE FUN MIMO
6. Eng: May I invite you, Abubakar, If only you could answer, To that will give you pleasure. you had better listen to reason!
Yoruba: Mo pe ire Abubakar ko ba da kio dami lohun, Lo sibi ti orire re wa, ti o ba se laakaye ni
7. Eng: To some knowledge which will make you a leader, Who is obeyed if you forbid or command
Yoruba: Mon pe o losibi mimo ti oo fidi asiwaju, Ti aye o maa tara re tele ti o ba ko fun awon eniyan kuro nibi aburu ati igba ti o ba pawon lase daadaa
8. Eng: It (knowledge) removes the covering on your eyes, And shows you the way whenever you stray
Yoruba: Mope sibi mimo ti yoo tanmole si gbogbo talubo oju re, Mimo yii ni naa yoo fi ona mo e nibi awon nnkan