وقفة
9. الباب الثالث · page 68 / 31
ti oo mo tele
9. Eng: Through it you bear a crown among your peer, As it also gets you clothed with beauty when you are stripped.
Yoruba: Yoo maa de o lade ni aarin ogooro awon eniyan. Yi o si maa wo e ni aso iyin nigba ti o ba wa ni ihoho.
10. Eng: You earn its benefits as long as you live, And you will be remembered for it when you die.
Yoruba: O o maa jere mimo yii lopin igba ti o ba si wa laye, Iranti mimo yii yoo si maa seku fun o koda bi o ba ti ku.
11. Eng: It is (like) the Indian sword that not does not miss; You use it to hit whomever you aim at their most vulnerable spot.
Yoruba: Ida kan ni mimo yii je ti o mu bere bere bi eyi ti a se ni India ti kii kulenu, O maa fii jeri eniti o ba gbero lati baja.
12. Eng: It is a treasure for which you fear no robber, Very portable, available wherever you are,
Yoruba: Pepe oro kan ni mimo je toole beru pe boya ole le, jiigbe,
Eru ti o fuye si ni o je ti o maa rilo ni gbogbo ibi kibi.
13. Eng: It increase by expending much of it

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru