وقفة
9. الباب الثالث · page 69 / 31
And it decreases if you withhold it.
Yoruba: Yi o maa lekun bi o ba se n loo si, Yio si maa dinku ti o ba di mowo ti oo naa fun awon eniyan.
14. Eng: If you have had a taste of its sweetness, You would have preferred learning and worked hard.
Yoruba: Ti o ba jepe o to adun kan wo ninu adun mimo ri, ni O o ba gbola fun wiwa mimo oo ba si se Igbiyanju riri mimo.
15. Eng: You would neither have been diverted from it by, overwhelming desire, Nor would you have been seduced by the vanities of this world.
Yoruba:Ma je ki ife inu ti o maa wa tele ki o ko airoju ba e, Masi je ki aye pelu adun yoroyoro inu re ki o ko airoju ba e eyi ti won fe fi ko wahala ba e.
16. Eng: You would neither have been distracted by elegant meadows, Nor would you have fallen in love with the finery of the boudoir.
Yoruba: Ma je ki abata ere kan ki o ko igbagbe ba e, Ma si je ki obinrin elete pelu awon eso re ki o ko igbagbe ba e debi ti oo ma wa jeran re.

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru