43. Eng: He (your lord) has gotten for you many good things with him, If (only) you remain in the courtyard of his obedience.
Yoruba: Daadaa wo ni o be fun o lodo olola?
Nigbati o ba taku si gbagba iwaju ile re nibi itele re
44. Eng: Accept my words of advice with willingness. For if you shun it you will get lost.
Yoruba:Gba oro mi yii daadaa Nigba ti o bag be oro mi yii ju sile o ti pofo ni yen o.
45. Eng: But if you comply with it by world and deed, And trade with god through it, you will gain.
Yoruba: Nigbati ti o ba so oro mi yii ni gbigbo ati lilo, O ti ba olohun sowo oo si di dandan kojere.
ASCETISM AND WORLDLY MATERIALISM AND ITS VANITY
IRI AIYE SA
46. Eng: This worldly life is nothing at all; It displeases you for a long time but please you only for a while.
Yoruba:Ile aye yii ko ja mo nkan kan, Yoo maa dun o ninu nigbakany oo si maaa ba o, ninu je nigba miran
47. Eng: The utmost (it can offer you) if you ponder over it, Is just like an (afternoon) shadow (does) or a dream