39. Eng:Indeed if the rich one should sit on cushions, You have already on the stars.
Yoruba: Ti olola ba joko lo ite olare, Eyi ti o da fun onimimo ni ki o maa se faari pe oun naa joko sori irawo giga lodo Olohun.
40. Eng: And if he should ride on a well-groomed and well-trained horse, You have already ridden on a well-trodden path of piety.
Yoruba: Nigba ti o ba joko lori esin ti a ko eso ba ti o fin se faari Iwo naa maa se faari pelu pe on gunaaye ipaya olohun oba.
41. Eng: No matter how many beautiful virgins he has deflowered, Any a virgin field of wisdom have you already deflowered.
Yoruba: Ti olola ba n se faari pelu jijabale awon omo obrinrin Iwo omnimimo naa maa se faari pelu pe melo melo imo tun tun ti iwo naa ti jabale.
42. Eng:Poverty will do you no harm at all, So long as you known your lord.
Yoruba:Osi o lee ni e lara lona kokan, Nigbati ti o ba mo Olohun re daadaa.