وقفة
9. الباب الثالث · page 74 / 31
Yoruba:Kosi riroro lodo awon eniyan fun alaimokan, Koda ki gbogbo ola hiraq o teriba fun-un
35. Eng:Erecting (lofty) buildings is no use to you, If you ruin your life with ignorance.
Yoruba: Kiko awon ile nla ko lee ro e loro, Nigba ti o ba ti wole mi arare pelu aimokan
36. Eng: You place wealth above knowledge out of sheer ignorance.mI swear you are not just with this decision (of yours)
Yoruba: O gbe owo leke mimo niti aimokan, Mo fi isemi re bura (o mase o!) o o se deede nibi idajo ti o da yen.
37. Eng: There is a difference between the two according to the text of the revelation; You will get to know of this if you read (surah) Toha.
Yoruba: opinyanwa laarin mejeeji pelu aya al-qur'an, Ogo pada mo nigba ti o ba ka surat toha
38. Eng: Indeed if the rich one should raise the banner of wealth, You have already raised the banner of knowledge.
Yoruba: Ti olola banta asia owo re soke Eyi ti o da fun onimimo ni ki ounna ta asia mimo re naa soke

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru