ka'bamo yen
30: Eng: If you see your mates in high positions, As they have risen above you while you are lowly,
Yoruba: Nigbati ti o ba ri awon ore e ni ipo tioga, Ti won ti ga ju e lo ti wo de wa ni isale
31. Eng:Then, turn to it (my advice) without any delay, For you cannot achieve your wish by any further delay (in turning to it).
Yoruba: Seri pada sibi oro mi ki o si pa ifakunukunu ti, Kii se pelu ifakunukun ni eniyan maa fi n ri ohun ti o ba n wa.
KNOWLEDGE VERSUS MONEY: AN APPRAISAL
IGBEYEWO AJULO TINBE LARIN OWO ATI MIMO
32. Eng: Do not be proud of your wealth but pay no attention to it. Wealth is nothing but what you have acquire (of knowledge.
Yoruba: Mase marin arinyan pelu owo re, ki osi gunri kuro nibe, Kii se owo ni o lese ayafi imo ti eniyan bani.
33. Eng: An ignorant one cannot be of help to people, Even if he becomes the king of Iraq.
34. Eng: Your knowledge will speak well of you before the whole world, But if you conceal it, this will someday be written against you.