ADMONITION AND WISDOM
ITANIJI ATI AWON ORO OGBON
21. Eng: Really, the peak of knowledge is the fear Allah, And not what is said (about you) that; "you have become a leader."
Yoruba: Akori mimo ni ipaya olohun oba niti ododo,Kii se ki won maa ni wipe iwo naa je olori.
22. Eng :The best of your clothing is that of good deeds, But I can see you have already worn the clothing of misdeed.
Yoruba: Eyi ti o fi n lola ju ninu aso re oun naa ni daadaa, sugbon aso aburu ni anri lorun ti e
23. Eng: If you do not make good use of knowledge, It would have been better for you to be ignorant
Yoruba: Nigbati ti mimo o baa se o lanfaani daada mo, O loore fun o ki o kuku je alaimokan
24. Eng: And if you understand should throw you into an abyss; I strongly wish you had not learnt at all
Yoruba:Nigbati ti agboye re (mimo) ba ju o si aarin jindojindo ina, O ma se fun o o ma se fun o nibi ohun ti o gboye ti oo lo.
25. Eng:. You will reap ignorance as the fruit of failure (to learn),