52. Eng:You have not been created to live in it forever, But to traverse it. So strive earnestly for what you have been created.
Yoruba: Won o da o pe ki o maa be ni aye gbere sugbon, Ki o kan le koja nibe lasan, Ki o si ki o kan le koja nibe lasan ki o si ya se gbiyanju lori ohun ti won tori e da e.
53. Eng: If it ruins you, then you ruin it the more, And strengthen the affair of your religion as much as you could.
Yoruba: Nigbati awon kan ba wo aye lokan won iwon naa, yaa kun won nibi wiwo aye, Ki o si so oro esin re bi o ba se lagbara mo.
54. Eng: Do not grieve over what you have missed in it, So far as you have succeeded regarding your afterlife.
Yoruba: Ma banuje lori nnkan to ba bo fun e ninu re, Nigbati to je pe oo pada je re nigbeyin re.
55. Eng: Whatever ephemeral things you acquire in it is of no benefit, If you are deprived of the everlasting life.
Yoruba: Gbogbo ohun ti o ba jeere ninu aye asan yi ko se anfaani, Lopin igba ti won ba ti hanna al-qiyamat fun o
56. Eng: Do not laugh (at my advice) with the fools at all,