Because you will soon cry if you do.
Yoruba: Ma maa rerin pelu awon omugo lojoo jumo, Nitori pe wa pada sukun lori erin re yen.
57. Eng: Who could make you happy while you are a hostage, As you do not know whether you will be ransomed or handcuffed?
Yoruba: Kilo dun e ninu? iwo ti a fi dogo, O o mo boya won a pada tukun kuro lorun re abi o maa be lo gbere ninu ide.
ETIQUETTES OF SUPPLICATION
AWON EKO BIBELORUN
58. Eng:Ask for success from your lord in it (this worldly life), And be sincere in your request while you make it (the request).
Yoruba: Beere ifinise konge oore lowo Olohun oba re ninu aye, Ki o si se mimo nibi ibeere ti o ba beere.
59. Eng: Call on him when you prostrated to him in acknowledgement (of your shortcoming), With what dhu-nun (jonah) son of Matta has called on him.
Yoruba: Pe Olohun oba nigbati o ba fi ori bale fun ni eni ti o jewo ese re.