وقفة
9. الباب الثالث · page 80 / 31
Pe pelu ohun ti dhu-nun bn matta (Anobi Yunus) fi pe Olohun re
60. Eng: Keep knocking on his door perhaps; He will open the door for you if you insist.
Yoruba: Dunni mo kikan lekun olohun re dandan ni, Ki o pada sinlekun fun e ti o ban kan-an
61. Eng: Remember him a lot on earth habitually; So that you will be remembered in the heaven as you do (remember him).
Yoruba: Po ni eniti yoo maa ranti olohun oba titi ti o yoo fi di isesi re, Ki won bale ma ranti re ni sanmo bi o ba ti n ranti olohun oba laye.
62. Eng: Do not say that youth is a grant of respite, But think of how you have buried many a youth
Yoruba: Ma maa sope omo kekere ni o nitori ifakunukun nbe nibe, Ki o si ronu wipe melo melo omo kekere egbere ti e ti sin.

THE REPLY
FIFO ESI (SI EBU)

63. Eng: You (may) say: you are more deserving of your advice, If only you have reflected on your deed.
Yoruba: Sope! Mo pe iwo ti o n se waasi fun mi iwo ni o

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru