105. Eng: Do not stay in a place where there is wrong doing, Because it kills the mind except if you are tied there.
Yoruba: Ma se duro si aaye ti aburu bawa to jepe yoo mapa okan ni ayaafi ti won ba deyan mole nibe.
106. Eng: Go eastward for doing so is better, Or go eastwards if you have suck up your saliva.
Yoruba: Ki o wa lo di ajoji nitori pe nibe ni oore wa Ki o wa duro nibi ti oorun ti yo to ba jepe nibe ni etimo re tin yo.
107. Eng: Renouncing worldly pleasure is not a burden, For you will become a prince for so doing (renouncing pleasure in worldly things).
Yoruba: Kii se ki eniyan pa laakaye re kuro ninu aye lo n je iraye sa, Sugbon ti o ba le raye sa, ooti be di asiwaju.
108. Eng: You could even rise above being a prince, In height and loftiness of your position.
Yoruba: Koda ti nnkan miran ba wa leyin asiwaju ibe loo wa, Niti giga ati idagbasoke loo maa be.
109. Eng: If you depart it (this world) and leave it (finally), For the home of peace (the hereafter) you have become safe.
Yoruba: Ti o ba sepa kuro ninu aye, ti o wa jade kuro ninu