الخاتمة
Contents
Chapter 51

الخاتمة

Share
No verses match your search
1

خاتمة قال الشيخ الرئيس أبو محمدٍ القاسِم بن علي برد اللهُ مضجعه:


English

Final words: Sheikh The Leader Abu Muhammad Al-Qasim bin Ali, may Allah cool his grave, said:

Yoruba

Ìparí: Àgbà Òní mimọ Bàbá Muhammad Kasim ọmọ Ali, kí Ọ̀lọ́hún jẹ kí saare rẹ tuutu, sọ pé:

2

هذا آخِر المَقاماتِ التي أنشأتها بالاغْتِرار.ِ وأملَيتها بلِسانِ الاضطِرار.ِ


English

This is the last of the Assemblies I created with deception. I elaborated it with the language of necessity.

Yoruba

Èyí ni ìkẹ̀yìn àwọn Makama tí mo hún pẹ̀lú ọgbọn ẹwẹ. Mo ṣàlàyé rẹ̀ pẹ̀lú èdè ọranyan.

3

وقد أُلجِئْت الى أن أرصدتها للاستِعراض.ِ وناديت عليها في سوقِ الاعتِراض.


English

And I was compelled to set it aside for review, and I called out to it in the marketplace of objections.

Yoruba

Mo sì fi ẹ̀tọ́ rẹ̀ sẹ́yìn fún àtúnyẹwò, mo sì kéde lé lórí ní ọjà àtakò.

4

هذا مع معرِفَتي بأمن سقَطِ المَتاع.ِ ومما يستوجِب أنْ يباع ولا يبتاع.


English

This is despite my knowledge of the safety of the item’s fall, and of what deserves to be sold but not bought.

Yoruba

Èyí pẹlú ìdánilójú mí nípa amojuto kí nkán igbadun má já bọ́. àti ohun tí ó yẹ kó jẹ́ pé a máa tà, ṣùgbọ́n kì í ṣe pé a tà.

5

ولو غشِيني نور التوفيق.ِ ونظرت لنفْسي نظر الشفيق.


English

Even if I had been blessed with the light of fortune and had looked upon myself with compassion.

Yoruba

Kò dà bí Imọlẹ kongẹ bá bomí, àti bí mo bá wo ara mi pẹ̀lú ojú àánú.

6

لسترت عواري الذي لمْ يزلْ مستوراً. ولكِن كانَ ذلِك في الكِتابِ مسطوراً.


English

I would have covered the flaws that are still hidden, but this was already written in the Book.

Yoruba

Èmi kò bá tí bó láìfí mí tí ó wà ní ìpamọ́, ṣùgbọ́n o tí nbẹ́ ni a kọ́ lẹ nínú Ìwé.

7

وأنا أسغفِر اللهَ تعالَى مما أودعتها من أباطيلِ اللّغو.ِ وأضاليلِ اللّهو.


English

And I ask Allah the Most High for forgiveness for what I have included of falsehood and frivolity.

Yoruba

Mo sì béèrè fún aforiji lọ́dọ̀ Allah Ọba Gíga fún ohun tí mo fi kún nínú àwọn aṣìṣe ọrọ àti ìdárayá ánu.

8

وأسترشِده الى ما يعصِم من السهو.ِ ويحظي بالعفْو.


English

And I seek His guidance to what protects from error and grants pardon.

Yoruba

Mo sì ń wá ìtọ́sọ́nà Rẹ̀ sí ohun tó máa dáàbò bo mí lọ́wọ́ aṣiṣe tí yóò sì mú mí rí amojukuro

9

إنه هو أهلُ التقْوى وأهلُ المَغفِرة.ِ ووليُّ الخيراتِ في الدنيا والآخِرة.ِ


English

Indeed, He is the one deserving of piety and forgiveness, and the patron of goodness in this world and the Hereafter

Yoruba

Ní tòótọ́, Òun ni ẹni tí ó yẹ kí a paya tí yóò sí d'áríjì ẹni, àti olùṣàkóso gbogbo awọn ore ní ayé yìí àti ní Ọjọ ìkẹhìn.

© , Qatru