They are the ones who let springs of generosity flow, sheltering those stripped or seeking refuge.
Wọ́n ni àwọn èèyàn tí ń jẹ́ kí orísun ọlá ṣàn, ń dáàbò bo ẹni tí kò ní ohunkóhun tàbí ẹni tí ń wá ààbò.
They are those who subdued the proud challenger, and straightened the arrogant and the wayward.
Wọ́n ni àwọn ní wọ́n ṣẹgun ẹni tí ń ṣe àtakò, wọ́n sì tọ́jú ẹni tí ó ń fi ìgbéraga hàn àti ẹni tí ó yí padà.
They are those who made whoever opposed them drink cups of humiliation, bitter draughts of hardship.
Wọ́n ni àwọn tí wọ́n jẹ́ kí ẹni tí ó dojú kọ́ wọn mu àgọ́ ìtẹ̀ríba, omi ìrora tó kún fún ìbànújẹ.
I will not remove the stuffing of a woven armor until I am hidden among heaps of corpses.
Èmí ko ní bọ ẹ̀wu irin tí a hun dáadáa, títí tí má fii wà ní apamọ́ láàárín àwọn oku.
My companions are sharp in their strength, like the paths of ants rising upon the hills.
Àwọn ọ̀rẹ́ mi méjèèjì, ọkan mú bere níbí agbára rẹ, bí ọnà àwọn awurebe tí ń gòkè lórí òkè.
White as salt when unsheathed, its edge meets nothing without cutting through.
Ó funfun bí iyọ̀ nígbà tí a bá yọ́ ọ́, kò ní pàdé ohunkóhun àyàfi í kò gé.
As though between its middle and edge, lies an oven of fire consumed by embers.
Bí ẹni pé láàárín rẹ àti etí rẹ̀, ilé iná kan wà tí ògúná ti jẹ.
He shows death, when it follows his trail, paths unseen in the darkness of hearts.
Ó fi ikú hàn, nígbà tí ó ń tẹ̀lé ipa rẹ̀, ní ojú-ọ̀nà tí a kò rí nínú òkùnkùn ọkàn.
When he strikes into a body, he leaves it after it was strong, now wasted.
Nígbà tí ó bá kọlu ara kan, ó fi sílẹ̀ lẹ́yìn tí ó jẹ́ alágbára, tí ó di ẹni tí kò ní agbára mọ́.
And (my second friend) the overseer of lands, its meat is heavy, protuded waist, broad chest, strong muscle.
Ọ̀rẹ́ Kejì ní Olùṣọ́ ilẹ̀, ẹ̀ran rẹ̀ pọ́, ẹgbẹ rẹ yọ jáde síta, ìgbaaya rẹ fẹ, iṣan àrà rẹ lé púpọ.