Chapter 1

اللفظ

No verses match your search
1

اللَّفْظُ الدَّالُّ بِالْوَضْعِ يَدُلُّ عَلَى تَمَامِ مَا وُضِعَ لَهُ بِالْمُطَابَقَةِ، وَعَلَى جُزْئِهِ بِالتَّضَمُّنِ إِنْ كَانَ لَهُ جُزْءٌ، وَعَلَى مَا يُلَازِمُهُ فِي الذِّهْنِ بِالْالْتِزَامِ كَالْإِنْسَانِ.


English

The word that its conventional indicative expression signifies the entirety of that for which it was coined by correspondence (muṭābaqah), and its part by inclusion (taḍammun) if it has a part, and what accompanies it in the mind by necessary implication (iltizām), like "human being."

Yoruba

Gbólóhùn tí ń tọ́ka sí gbogbo ohun tí a yàn án fún nípa ìbámu (muṭābaqah), àti sí apá kan rẹ̀ nípa ìfihàn (taḍammun) bí ó bá ní ipín kan, àti sí ohun tí ó bá a mu nínú làákàyè ní (iltizām), bí "èèyàn."

2

فَإِنَّهُ يَدُلُّ عَلَى الْحَيَوَانِ النَّاطِقِ بِالْمُطَابَقَةِ، وَعَلَى أَحَدِهِمَا بِالتَّضَمُّنِ، وَعَلَى قَابِلِيَّةِ الْعِلْمِ وَصَنْعَةِ الْكِتَابَةِ بِالْالْتِزَامِ.


English

For it signifies the rational animal by correspondence, and also one of its two (parts) by inclusion, and the capacity for knowledge and the craft of writing by necessary implication.

Yoruba

Nítorí pé ó ń tọ́ka sí ẹranko òní ọ̀gbọ́n nípa ìbámu, àti sí ọ̀kan lára wọn (apá méjèèjì) nípa ìfihàn, àti sí gbígba-ìmọ̀ àti iṣẹ́ kíkọ nípa ìtẹ̀lé.

3

ثُمَّ اللَّفْظُ إِمَّا مُفْرَدٌ: وَهُوَ الَّذِي لَا يُرَادُ بِالْجُزْءِ مِنْهُ دِلَالَةً عَلَى جُزْءِ مَعْنَاهُ كَالْإِنْسَانِ. وَإِمَّا مُؤَلَّفٌ: وَهُوَ الَّذِي لَا يَكُونُ كَذلِكَ كَرَامِي الْحِجَارَةِ.


English

Then the expression is either simple (mufrad): that which does not intend by its part to indicate a part of its meaning, like "human being"; or composite (muʾallaf): that which is not like that, like "throwing stones."

Yoruba

Lẹ́yìn náà, ọ̀rọ̀ náà jẹ́ pin sí oríṣi méjì: ọ̀rọ̀ àdákọ (mufrad): èyí tí apá kan rẹ̀ kò tọ́ka sí apá kan ìtumọ̀ rẹ̀, bí "èèyàn"; tàbí ọ̀rọ̀ àkópọ̀ (muʾallaf): èyí tí kò rí bẹ́ẹ̀ (apá kan rẹ tọ̀ká sí apá kan ìtumọ rẹ, bí "Òlùjú òkúta."

4

فَالْمُفْرَدُ إِمَّا كُلِّيٌّ: وَهُوَ الَّذِي لَا يَمْنَعُ نَفْسُ تَصَوُّرِ مَفْهُومِهِ عَنْ وُقُوعِ الشَّرِكَةِ فِيهِ، كَالْإِنْسَانِ. وَإِمَّا جُزْئِيٌّ: وَهُوَ الَّذِي يَمْنَعُ نَفْسُ تَصَوُّرِ مَفْهُومِهِ عَنْ ذلِكَ، كَزَيْدٍ.


English

So the simple (term) is either universal (kullī): that whose concept does not prevent participation in it, like "human being"; or particular (juzʾī): that whose concept does prevent that, like "Zayd."

Yoruba

Nítorí náà, ọ̀rọ̀ àdákọ pin sí oríṣi méjì: ọ̀rọ̀ gbogbogbòò (kullī): èyí tí ìrisí agbọye rẹ̀ kò dènà ìkópa míràn nínú rẹ̀, bí "èèyàn"; tàbí ọ̀rọ̀ ìpín (jusʾī): èyí tí ìrònú agbọye rẹ̀ dènà òmíràn, bí "Seidu."

5

وَالْكُلِّيُّ إِمَّا ذَاتِيٌّ: وَهُوَ الَّذِي يَدْخُلُ فِي حَقِيقَةِ جُزْئِيَّاتِهِ، كَالْحَيَوَانِ بِالنِّسْبَةِ إِلَى الْإِنْسَانِ وَالْفَرَسِ. وَإِمَّا عَرَضِيٌّ: وَهُوَ الَّذِي بِخِلَافِهِ، كَالضَّاحِكِ بِالنِّسْبَةِ إِلَى الْإِنْسَانِ.


English

And the universal is either essential (dhātī): that which enters into the reality of its particulars, like "animal" in relation to human and horse; or accidental (ʿaraḍī): that which is contrary to that, like "laughing" in relation to human.

Yoruba

Ọ̀rọ̀ gbogbogbòò yìí náà pin sí oríṣi méjì: ọ̀rọ̀ ìdánilójú (ssātī): èyí tí ó wọ inú pàápàá àwọn ìpín rẹ̀, bí "ẹranko" ní ìbámu pẹ̀lú èèyàn àti ẹṣin; tàbí ọ̀rọ̀ (ʿaraḍī): èyí tí ó yàtọ̀ sí ìyẹn, bí "ẹ̀rín" ní ìbámu pẹ̀lú èèyàn.

6

وَالذَّاتِيُّ إِمَّا مَقُولٌ فِي جَوَابِ مَا هُوَ بِحَسَبِ الشَّرَكَةِ الْمَحْضَةِ — كَالْحَيَوَانِ بِالنِّسْبَةِ إِلَى الْإِنْسَانِ وَالْفَرَسِ — وَهُوَ الْجِنْسُ: وَيُرْسَمُ بِأَنَّهُ كُلُّ مَقُولٍ عَلَى كَثِيرِينَ مُخْتَلِفِينَ بِالْحَقَائِقِ فِي جَوَابِ مَا هُوَ قَوْلًا ذَاتِيًّا.


English

And the essential (universal) is either said in answer to "what is it?" according to pure commonality—like "animal" in relation to human and horse—and it is the genus (jins): defined as that which is predicated of many differing in realities in answer to "what is it?" in an essential manner.

Yoruba

Ọ̀rọ̀ ìdánilójú jẹ́ àyàtọ̀ sí oríṣi: èyí tí a ń sọ ní ìdáhùn sí "kí ni?" ní ìbámu pẹ̀lú ìfara-pọ̀ nìkan—bí "ẹranko" ní ìbámu pẹ̀lú èèyàn àti ẹṣin—òun ni iran (jins): a túmọ̀ rẹ̀ sí ohun tí a ń sọ fún ọ̀pọ̀ tí ó yàtọ̀ ní àwọn òtítọ́ wọn ní ìdáhùn sí "kí ni?" ní ọ̀nà ìdánilójú.

7

وَإِمَّا مَقُولٌ فِي جَوَابِ مَا هُوَ بِحَسَبِ الشَّرِكَةِ وَالْخُصُوصِيَّةِ مَعًا — كَالْإِنْسَانِ بِالنِّسْبَةِ إِلَى زَيْدٍ وَعَمْرٍو — وَهُوَ النَّوْعُ: وَيُرْسَمُ بِأَنَّهُ كُلُّ مَقُولٍ عَلَى كَثِيرِينَ مُخْتَلِفِينَ بِالْعَدَدِ دُونَ الْحَقِيقَةِ فِي جَوَابِ مَا هُوَ.


English

Or (it is) said in answer to "what is it?" according to both commonality and specificity together—like "human being" in relation to Zayd and ʿAmr —and it is the species (nawʿ): defined as that which is predicated of many differing in number but not in reality in answer to "what is it?"

Yoruba

Tàbí èyí tí a ń sọ ní ìdáhùn sí "kí ni?" ní ìbámu pẹ̀lú ìfara-pọ̀ àti àkànṣe pọ̀—bí "èèyàn" ní ìbámu pẹ̀lú Seidu àti ʿAmr —òun ni irú (nawʿ): a túmọ̀ rẹ̀ sí ohun tí a ń sọ fún ọ̀pọ̀ tí ó yàtọ̀ ní òǹkà ṣùgbọ́n kì í ṣe ní pàápàá wọn níbí ìdáhùn sí "kí ni?"

8

وَإِمَّا غَيْرُ مَقُولٍ فِي جَوَابِ مَا هُوَ، بَلْ مَقُولٍ فِي جَوَابِ أَيُّ شَيْءٍ هُوَ فِي ذَاتِهِ — وَهُوَ الَّذِي يُمَيِّزُ الشَّيْءَ عَمَّا يُشَارِكُهُ فِي الْجِنْسِ، كَالنَّاطِقِ بِالنِّسْبَةِ إِلَى الْإِنْسَانِ — وَهُوَ الْفَصْلُ: وَيُرْسَمُ بِأَنَّهُ كُلُّ مَقُولٍ عَلَى الشَّيْءِ فِي جَوَاب" أَيُّ شَيْءٍ هُوَ فِي ذَاتِهِ".؟


English

Or (it is) not said in answer to "what is it?" but rather in answer to "what sort of thing is it in its essence?"—and it is that which distinguishes the thing from what shares its genus, like "rational" in relation to human —and it is the differentia (faṣl): defined as that which is predicated of the thing in answer to "what sort of thing is it in its essence?"

Yoruba

Tàbí èyí tí a kì í sọ nípa ìdáhùn sí "kí ni?" bí kò ṣe pé a ń sọ ọ́ ní ìdáhùn sí "irú ohun wo ni ó jẹ́ nínú ẹ̀mí ara rẹ̀?"—òun ni èyí tí ń fi ohun ṣe ìyàtọ̀ pẹ̀lú ohun tí ó bá a pín iran, bí "ọ̀lọ́gbọ́n" ní ìbámu pẹ̀lú èèyàn —òhun ní a n pè ní Ìyàtọ̀ (faṣl): a túmọ̀ rẹ̀ sí ohun tí a ń sọ sí nkan ní ìdáhùn sí "irú ohun wo ni ó jẹ́ nínú ẹ̀mí ara rẹ̀?"

9

وَالْعَرَضِيُّ إِمَّا أَنْ يَمْتَنِعَ انْفِكَاكُهُ عَنِ الْمَاهِيَّةِ، وَهُوَ الْعَرَضُ اللَّازِمُ. أَوْ لَا يَمْتَنِعَ، وَهُوَ الْمُفَارِقُ.


English

And the accidental (universal) is either that which cannot be separated from the essence—and it is the inseparable accident (ʿaraḍ lāzim); or it is not impossible—and it is the separable (accident).

Yoruba

Ọ̀rọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣẹ́ríwá (Àràdí) pin sí oríṣi: bóyá kí pínpín rẹ kúrò nínú pàápàá (māhiyyah)—òun ni ìṣẹ̀lẹ̀ ìṣẹ́ríwá aláìyà (ʿaraḍ lāzim); tàbí kò jẹ́ pé kò kọ làti yà—òun ni ìṣẹ̀lẹ̀ ìsẹ́ríwá olùyà.

10

وَكُلُّ وَاحِدٍ مِنْهُمَا إِمَّا أَنْ يَخْتَصَّ بِحَقِيقَةٍ وَاحِدَةٍ — وَهُوَ الْخَاصَّةُ — كَالضَّاحِكِ بِالْقُوَّةِ وَالْفِعْلِ لِلْإِنْسَانِ. وَتُرْسَمُ بِأَنَّهَا كُلِّيَةٌ تُقَالُ عَلَى مَا تَحْتَ حَقِيقَةٍ وَاحِدَةٍ فَقَطْ قَوْلًا عَرَضِيًّا.


English

And each of the two is either specific to one reality—and it is the proper accident (khāṣṣah)—like "capable of laughing potentially and actually" for human. And it is defined as a universal that is predicated of what is under a single reality only, in an accidental manner.

Yoruba

Olúkúlùkù nínú méjèèjì jẹ́ orísirísi: bóyá ó kan òtítọ́ kan ṣoṣo—òun ni àkànṣe-ìṣẹ̀lẹ̀ (khāṣṣah)—bí "Ẹ̀lẹ́rín ní agbára àti ní ìṣe" fún èèyàn. A sì túmọ̀ rẹ̀ sí ohun gbogbogbòò tí a ń sọ sí ohun tí ó wà lábẹ́ pàápàá òtítọ́ kan ṣoṣo nìkan, ní ọ̀nà ìṣẹ́ríwá.

© , Qatru
Qatru presents public-domain classical texts and modern library works shared with permission where applicable.