Suʿād has departed, so my heart today is ill —lovesick, following her, its captive has not been ransomed.
Suʿād ti lọ, nítorí náà, ọkàn mi lónìí jẹ́ ohun tí ó ṣe àárẹ —tí ń nifẹ, tó ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn, tí wọ́n kò ti rí ìgbàlà fún ohùn tí wọ́n dé mọlẹ.
And what is Suʿād, on the morning of parting when they departed, but a sweet-voiced one with downcast, kohl-darkened eyes?
Kí ni Suʿād, ní òwúrọ́ ìrìnàjò rẹ nígbà tí wọ́n lọ, bí kò ṣe ẹni tí ó ní ohùn dídùn, tí ó rẹ́ ojú sílẹ̀, tí ó fi Tìro le ojú rẹ̀?
A slender-waisted one when she approaches, full-hipped when she turns away—neither shortness nor tallness is complained of in her.
Ẹni tí Ó tẹrẹ ní nígbà tí ó bá ń bọ̀, tí ẹ̀yìn rẹ̀ sì kún nígbà tí ó bá yí padà—wọn kì ń kígbe kúkúrú tàbí gígùn nípa rẹ̀.
She reveals bright cheeks when she smiles—as if they were a watering-hole mixed with pure wine.
Ó ń fi ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀ tí ó mọ́lẹ̀ hàn nígbà tí ó rẹ́rìn-ín—bí ẹni pé wọ́n jẹ́ omi-ọ̀gbà tí a dà pọ̀ pẹ̀lú wáìnì mímọ́.
It was mixed with coldness from the water of Maḥniyah—pure, in a valley, that became encompassed by winds.
Wọn fi òtútù ropọ pẹ̀lú omi Maḥniyah—ti ó mọ́, ní àfonífojì kan, tí afẹ́fẹ́ yí ká.
The winds clear the dust from it, and (rain) from a night-pouring cloud, white and cold, also cleanses it.
Afẹ́fẹ́ ń fọ erùpẹ̀ kúrò lórí rẹ̀, omi láti inú kùrukùru alẹ́, funfun ti o òtútù, náà sì ń fọọ mọ.
Woe to her as a close friend—if only she had been true to what she promised, or if only good counsel were accepted!
Ègbé ni fún un gẹ́gẹ́ bí ọ̀rẹ́ ayo —ìbáṣe pé ó jẹ́ olóòótọ́ sí ohun tí ó ṣèlérí, tàbí ìbáṣe pé ìmọ̀ràn dídára jẹ́ ohun tí ó jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà!
But she is a friend in whose blood was mixed calamity, obsessive passion, broken promises, and change.
Ṣùgbọ́n ó jẹ́ ọ̀rẹ́ tí a ti dà pọ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀: àjálù, ìfẹ́-ọkàn àìdánilójú, ìyapa àdéhùn, àti ìyípadà.
So she does not remain in any state she is in—just as the masquerade changes colors in its garments.
Nítorí náà, kò ki ń dúró ní ipò kankan tí ó wà—gẹ́gẹ́ bí ẹ̀mí Eégún ṣe ń yí àwọ̀ padà nínú aṣọ ẹkú rẹ̀.
And she does not hold to the union she claimed—except as sieves hold water.
Bẹ́ẹ̀ ni kò kí ń dìrọmọ ìfẹ́ tí ó fẹ́ —bí kò ṣe bí àwọn ásẹ ṣe ń mu omi dání.