الباب الثالث
Contents
Chapter 3

الباب الثالث

Share
No verses match your search
41

مِنْهُ تَظَلُّ سِبَاعُ الْجَوِّ ضَامِزَةً.


English

From him the beasts of the air remain crouching still,

Yoruba

Láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn ẹranko afẹ́fẹ́ fi ń dùbúlẹ̀ ní ìdákẹ́jẹ́,

42

وَلَا تَمَشَّى بَوَادِيهِ الْأَرَاجِيلُ.


English

And the men of the wilderness do not walk in his domains.

Yoruba

Àwọn ènìyàn aginjù kò sì rìn nínú àwọn pápá rẹ̀.

43

وَلَا يَزَالُ بِوَادِيهِ أَخُو ثِقَةٍ.


English

And there remains in his valley a trusted brother,

Yoruba

Ẹ̀gbọ́n ẹ̀nìgbẹ́kẹ̀lé kan sì ń wà ní àfonífojì rẹ̀,

44

مُطَرَّحَ الْبَزِّ وَالدِّرْسَانِ مَأْكُولُ.


English

His war garments cast off, his clothes worn, devoured.

Yoruba

ti aṣọ ìjà rẹ̀ tí bọ sílẹ̀, aṣọ náà sì ti gbó, tí o sì ti dí jijẹ.

45

إِنَّ الرَّسُولَ لَسَيْفٌ يُسْتَضَاءُ بِهِ.


English

Indeed the Messenger is a sword by which light is sought,

Yoruba

Nítòótọ́, Òjíṣẹ́ jẹ́ idà tí a ń wá ìmọ́lẹ̀ nípasẹ̀ rẹ̀,

46

مُهَنَّدٌ مِنْ سُيُوفِ اللَّهِ مَسْلُولُ.


English

An Indian blade from among the swords of Allah, drawn.

Yoruba

Idà ilẹ̀ Íńdíà lára àwọn idà Ọlọ́run, tí a yọ jáde.

47

فِي فِتْيَةٍ مِنْ قُرَيْشٍ قَالَ قَائِلُهُمْ.


English

Among a group of youths of Quraysh, their speaker said,

Yoruba

Láàárín àwọn ọ̀dọ́ Kuraysh, olùsọ̀rọ̀ wọn sọ pé,

48

بِبَطْنِ مَكَّةَ لَمَّا أَسْلَمُوا زُولُوا.


English

In the valley of Mecca, when they submitted: "Depart!"

Yoruba

Ní àfonífojì Mekka, nígbà tí wọ́n fi ara wọn sílẹ̀: "Ẹ lọ!"

49

زَالُوا فَمَا زَالَ أَنْكَاسٌ وَلَا كُشُفٌ.


English

They departed, and there remained neither cowards nor weaklings,

Yoruba

Wọ́n lọ, kò sì sí ẹni tí ó jẹ́ ẹlẹ́gàn tàbí aláìlágbára tí ó kù,

50

عِنْدَ اللِّقَاءِ وَلَا مِيلٌ مَعَازِيلُ.


English

At the encounter, nor those who are yet to master how to fight or weaponless that are inclined to flee.

Yoruba

Ní àkókò ìjà, bẹ́ẹ̀ ni kò sí àwọn tí kò mọ bí wọn tí má ń jà, tí wọn kò ní nkán ìjà.

© , Qatru