Chapter 6

الْمَقَامَةُ الْمَرَاغِيَّةُ

51

المَأْثُورَةِ عَنْهُمْ لِتَقَادُمِ المَوَالِدِ


English

Inherited from them due to the antiquity of their origins

Yoruba

Tí a jogún lọ́wọ́ wọn nítorí pé wọ́n ti pẹ́

52

لَا لِتَقَدُّمِ الصَّادِرِ عَلَى الوَارِدِ


English

Not for the precedence of the source over the derivative?

Yoruba

Kì í ṣe tí ìṣáájú débi ọgbọ́ǹ ọrọ̀ ju èyí tó jáde wá lọ?

53

وَإِنِّي لَأَعْرِفُ الآنَ مَنْ إِذَا أَنْشَأَ


English

And indeed I know now one who when he composes

Yoruba

Nítòótọ́ mo mọ ẹnìkan báyìí tí ó bá kọ ǹkan

54

وَشَى


English

He embellishes

Yoruba

Ó ń ṣe é lọ́ṣọ́

55

وَإِذَا عَبَّرَ


English

And when he expresses

Yoruba

Tí ó bá sì sọ̀rọ̀

56

حَبَرَ


English

He enlightens

Yoruba

Ó ń ṣe àlàyé

57

وَإِنْ أَسْهَبَ


English

And if he elaborates

Yoruba

Tí ó bá sì sọ púpọ̀

58

أَذْهَبَ


English

He amazes

Yoruba

Ó ń ya ní lẹ́nu

59

وَإِذَا أَوْجَزَ


English

And when he is concise

Yoruba

Tí ó bá sì sọ díẹ̀

60

أَعْجَزَ


English

He incapacitates

Yoruba

Ó ń mú kí ẹnu ó yà wọ́n

© , Qatru