وقفة
9. الباب الثالث · page 66 / 31
CHAPTER THREE
In the name of Allah, the Beneficent, the Merciful
Youthful Exuberances: A detterences (the prelude)
LILENIKURO NIBI IMURARA IWA ODONDE

1. Eng: The days are surely weakening your heart
completely,
And time is fast exhausting your body.
Yoruba: Awon ojo aye re on run isemi re niti rirun
Awon wakati aye re ongbe ara re niti gbigbe

2. Eng: Death is calling on you really (saying):
Listen, my friend it is you I actually want
Yoruba: Iku npe o ni pipe ododo
Teti ki o gbo mo pe iwo ore mi, iwo ni mo gbero
lati pa

3. Eng:  I can see you love a woman in her boudoir,
Who has been totally forsaken by the wise.
Yoruba: Mori o ni eniti o nife obrinin (awelewa ton be ninu
ileso)
Awon ojogbon ti ko titele obinrin niti kiko.

4. Eng:Poor you, you sleep with her all year snoring;
You will not realized (the truth) until when you
are dead.
Yoruba:On fi gbogbo igbare sun sio re nibi ihanrun re yen
Pelu ihanrun re yen se o di igba ti o ba ku ki o to
laju ni.

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru