52. Eng:
Yoruba:
53. Eng:
You have not been created to live in it forever,
But to traverse it. So strive earnestly for what you
have been created.
Won o da o pe ki o maa be ni aye gbere sugbon
Ki o kan le koja nibe lasan
Ki o si ki o kan le koja nibe lasan ki o si ya se
gbiyanju lori ohun ti won tori e da e
If it ruins you, then you ruin it the more,
And strengthen the affair of your religion as much
as you could.
Yoruba: Nigbati awon kan ba wo aye lokan won iwon naa
54. Eng:
Yoruba:
55. Eng:
yaa kun won nibi wiwo aye
Ki o si so oro esin re bi o ba se lagbara mo
Do not grieve over what you have missed in it,
So far as you have succeeded regarding your
afterlife.
Ma banuje lori nnkan to ba bo fun e ninu re
Nigbati to je pe oo pada je re nigbeyin re
Whatever ephemeral things you acquire in it is of
no benefit, If you are deprived of the everlasting
life.
Yoruba: Gbogbo ohun ti o ba jeere ninu aye asan yi ko se
56. Eng:
anfaani
Lopin igba ti won ba ti hanna al-qiyamat fun o
Do not laugh (at my advice) with the fools at all,
ΥΛ
5