وقفة
9. الباب الثالث · page 75 / 31
39. Eng:
Yoruba:
40. Eng:
Indeed if the rich one should sit on cushions,
You have already on the stars.
Ti olola ba joko lo ite olare
Eyi ti o da fun onimimo ni ki o maa se faari pe oun
naa joko sori irawo giga lodo Olohun
And if he should ride on a well-groomed and
well-trained horse,
You have already ridden on a well-trodden path of
piety.
Yoruba: Nigba ti o ba joko lori esin ti a ko eso ba ti o fin se
faari
41. Eng:
Yoruba:
42. Eng:
Yoruba:
Iwo naa maa se faari pelu pe on gunaaye ipaya
olohun oba
No matter how many beautiful virgins he has
deflowered,
Any a virgin field of wisdom have you already
deflowered.
Ti olola ba n se faari pelu jijabale awon omo
obrinrin
Iwo omnimimo naa maa se faari pelu pe melo melo
imo tun tun ti iwo naa ti jabale.
Poverty will do you no harm at all,
So long as you known your lord.
Osi o lee ni e lara lona kokan
Nigbati ti o ba mo Olohun re daadaa

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru