Yoruba:
35. Eng:
Yoruba:
36. Eng:
Yoruba:
37. Eng:
Yoruba:
38. Eng:
Yoruba:
Kosi riroro lodo awon eniyan fun alaimokan
Koda ki gbogbo ola hiraq o teriba fun-un
Erecting (lofty) buildings is no use to you,
If you ruin your life with ignorance.
Kiko awon ile nla ko lee ro e loro
Nigba ti o ba ti wole mi arare pelu aimokan
You place wealth above knowledge out of sheer
ignorance.
I swear you are not just with this decision (of
yours)
O gbe owo leke mimo niti aimokan
Mo fi isemi re bura (o mase o!) o o se deede nibi
idajo ti o da yen
There is a difference between the two according to
the text of the revelation;
You will get to know of this if you read (surah)
Toha.
opinyanwa laarin mejeeji pelu aya al-qur'an
Ogo pada mo nigba ti o ba ka surat toha
Indeed if the rich one should raise the banner of
wealth,
You have already raised the banner of knowledge.
Ti olola banta asia owo re soke
Eyi ti o da fun onimimo ni ki ounna ta asia mimo
re naa soke
٧٤