Chapter 1

لامية الشنفرى

No verses match your search
11

ثَلَاثَةُ أَصْحَابٍ: فُؤَادٌ مُشَيَّعٌ وَأَبْيَضُ إِصْلِيتٌ وَصَفْرَاءُ عَيْطَلُ.


English

Three companions: a devoted heart, a gleaming sharp unsheathed sword, and a long-necked bow of yellow hue.

Yoruba

Àwọn ọrẹ mẹ́ta ni: ọkàn aṣotito, idà ( tí wọn yọ jáde kúrò nínú akọ) funfun tí ó mú, àti ọrun ọ̀fà ọ̀lọrùn gígùn.

12

هَتُوفٌ مِنَ الْمُلْسِ الْمُتُونِ تَزِينُهَا رَصَائِعُ قَدْ نِيطَتْ إِلَيْهَا وَمِحْمَلُ.


English

It is sonorous, from those with smooth backs, adorned with ornaments and a carrying-shealth tied upon it.

Yoruba

Ó ní ohùn ariwo, lára àwọn tí ẹ̀yìn wọn dán, tí àwọn ohun ọṣọ àti àpò akọ rẹ tí a so mọ́ ọn ṣe e lọ́ṣọ̀ọ́.

13

إِذَا زَلَّ عَنْهَا السَّهْمُ حَنَّتْ كَأَنَّهَا مُرَزَّأَةٌ عَجْلَى تُرِنُّ وَتُعْوِلُ.


English

When the arrow slips from it, it groans as if it were a bereaved, hasty woman who sobs and wails.

Yoruba

Bí ọfà bá yọ́ kúrò lórí rẹ̀, ó ń kùn bí ẹni pé obìnrin tó ṣọ̀fọ̀ ọmọ, tó yára, tó ń ṣàkún tó sì ń polówó.

14

وَأَغْدُو خَمِيصَ الْبَطْنِ لَا يَسْتَفِزُّنِي إِلَى الزَّادِ حِرْصٌ وَلَا فُؤَادٌ مُوَكَّلٌ.


English

I arise with hollow stomach, neither greed nor a tormented heart provokes me toward food.

Yoruba

Mo máa ń jí ní ààrọ̀, ikùn mi ṣófo, ojúkòkòrò kò darí mi sí oúnjẹ, bẹ́ẹ̀ ni kò si ọkàn tó ń dà mí láàmú.

15

وَلَسْتُ بِمِهْيَافٍ يُعَشِّي سَوَامَهُ مُجَدَّعَةً سُقْبَانُهَا وَهْيَ بُهَّلُ.


English

I am not a weakling who feeds his livestock at night, with their young ones mutilated while they are heedless.

Yoruba

Èmi kì í ṣe aláìlera tó máa ń bọ́ ẹran rẹ̀ lálẹ́, tí àwọn ọmọ wọn sì gbẹ́, tí wọn kò sì bìkítà.

16

وَلَا جُبَّأٍ أَكْهَى مُرِبٍّ بِعِرْسِهِ يُطَالِعُهَا فِي شَأْنِهِ كَيْفَ يَفْعَلُ.


English

Nor am I a cowardly, impotent man who clings to his wife, consulting her about his affair as to how he should act.

Yoruba

Bẹ́ẹ̀ ni èmi kì í ṣe ẹni tí ń wárìrì, aláìlera, tó ń naju pẹ̀lú iyàwó rẹ̀, tó máa ń bá a wá ìmọ̀ràn nípa ọ̀rọ rẹ̀ bí ó ṣe yẹ kó ṣe.

17

وَلَا خَرِقٍ هَيْقٍ كَأَنَّ فُؤَادَهُ يَظَلُّ بِهِ الْمُكَّاءُ يَعْلُو وَيَسْفُلُ.


English

Nor am I a foolish, tall man whose heart seems to be such that the whistling bird rises and falls within it.

Yoruba

Bẹ́ẹ̀ ni èmi kì í ṣe aṣiwèrè, gígan, tí ó dà bí ẹni pé ẹyẹ aládùn ń bọ́kọ̀ bọ́ sọ̀kalẹ̀ nínú ọkàn rẹ̀.

18

وَلَا خَالِفٍ دَارِيَّةٍ مُتَغَزِّلٍ يَرُوحُ وَيَغْدُو دَاهِنًا يَتَكَحَّلُ.


English

Nor am I a one who stays behind in the encampment, a flirt, spending his evening and morning anointed and applying kohl.

Yoruba

Bẹ́ẹ̀ ni èmi kì í ṣe olujoko sí ibùdó, olubaobinrin naju, tó ń ṣepe nìrọ̀lẹ́ àti lààrọ̀ ní O fi ń para, tó sì ń ṣe ara rẹ̀ lọ́ṣọ̀ọ́.

19

وَلَسْتُ بِعَلٍّ شَرُّهُ دُونَ خَيْرِهِ أَلَفَّ إِذَا مَا رُعْتَهُ اهْتَاجَ أَعْزَلُ.


English

Nor am I a man whose evil surpasses his good, one entwined who, when you startle him, he becomes unsettled, likewise he doesn't have weapon

Yoruba

Èmi kì í ṣe eegbọn tí ibi rẹ̀ ju rere rẹ̀ lọ, tí ó dì pọ̀, tí ó bá dẹ̀rù bá, yóò damu, kò sì tún lágbára

20

وَلَسْتُ بِمِحْيَارِ الظَّلَامِ إِذَا انْتَحَتْ هُدَى الْهَوْجَلِ الْعِسِّيفِ يَهْمَاءُ هَوْجَلُ.


English

Nor am I a confused person in darkness when the vast, swirling desert overcome the guide of the senseless lost fellow!.

Yoruba

Èmi kì í damu ninu ókùnkùn nígbà tí aṣálẹ̀ gbígbòòrò, bá kọdí imọna arákùnrin didinrin tó ń sọnu.

© , Qatru
Qatru presents public-domain classical texts and modern library works shared with permission where applicable.