Chapter 1

لامية الشنفرى

No verses match your search
21

إِذَا الْأَمْعَزُ الصَّوَّانُ لَاقَى مَنَاسِمِي تَطَايَرَ مِنْهُ قَادِحٌ وَمُفَلَّلُ.


English

When the hard stony ground meets my hoofs, sparks and pebbles flew out from it.

Yoruba

Nígbà tí ilẹ̀ olokuta líle tẹ́ bàtà mi, iná pẹlú òkúta wẹwẹ máa ń tà jáde láti inú rẹ̀.

22

أُدِيمُ مِطَالَ الْجُوعِ حَتَّى أُمِيتَهُ وَأَضْرِبُ عَنْهُ الذِّكْرَ صَفْحًا فَأُذْهَلُ.


English

I prolong the stretching of hunger until I kill it, and I turn away from its mention completely, so that I become oblivious.

Yoruba

Mo máa ń ṣe ìdánwò ebi lọ́nà pípẹ títí èmi yóò fi pa á, mo sì kọ ìrántí rẹ̀ sílẹ̀ pátápátá, tí èmi yóò fi gbàgbé é.

23

وَأَسْتَفُّ تُرْبَ الْأَرْضِ كَيْلَا يُرَى لَهُ عَلَيَّ مِنَ الطَّوْلِ امْرُؤٌ مُتَطَوِّلٌ.


English

I lick the dust of the earth so that no person who presumes to give may see that he has any favor over me.

Yoruba

Mo máa ń la erùpẹ̀ ilẹ̀ kí ẹnìkan tí ń má ń siregun, má bàa rí iregun ṣe lórí mi.

24

وَلَوْلَا اجْتِنَابُ الذَّأْمِ لَمْ يُلْفَ مَشْرَبٌ يُعَاشُ بِهِ إِلَّا لَدَيَّ وَمَأْكَلُ.


English

Were it not for avoiding blame, no drink or food by which one lives would be found except with me.

Yoruba

Bí kì í ṣe fún ìṣọra kúrò lọ́wọ́ èébú, kò ní sí ohun mímu tàbí oúnjẹ tí a fi ń ṣayè tí a lè rí, àyàfi lọ́dọ̀ mi.

25

وَلَكِنَّ نَفْسًا مُرَّةً لَا تُقِيمُ بِي عَلَى الذَّامِ إِلَّا رَيْثَمَا أَتَحَوَّلُ.


English

But a bitter soul does not stay with me upon disgrace except for a short while until I move away.

Yoruba

Ṣùgbọ́n ọkàn kíkorò kì í pẹ̀lú mi lórí ẹ̀gàn bí kì í ṣe fún ìgbà díẹ̀ títí èmi yóò fi yí padà.

26

وَأَطْوِي عَلَى الْخمْصِ الْحَوَايَا كَمَا انْطَوَتْ خُيُوطَةُ مَارِيٍّ تُغَارُ وَتُفْتَلُ.


English

I fold my intestines over emptiness just as a Marī thread is folded—dyed and twisted.

Yoruba

Mo máa ń kó àwọn ifun mi pa mọ́ lórí òfo (ebi) gangan bí obìnrin Maari tí fọwọ́ ń t ka okùn, tí wọ́n ń tà á, tí ó ní àro, tí wọ́n sì ń lọ.

27

وَأَغْدُو عَلَى الْقُوتِ الزَّهِيدِ كَمَا غَدَا أَزَلُّ تَهَادَاهُ التَّنَائِفَ أَطْحَلُ.


English

I go forth upon meager food just as a swift, sandy-colored camel goes forth—whom the deserts pass along one to another.

Yoruba

Mo máa ń jí lòwurọ lórí oúnjẹ tí ó kéré bí ràkúnmí aláwọ̀ iyanrìn tí ó yára, tí àwọn aṣálẹ̀ ń gbé fún ara wọn.

28

غَدَا طَاوِيًا يُعَارِضُ الرِّيحَ هَافِيًا يَخُوتُ بِأَذْنَابِ الشِّعَابِ وَيُعْسِلُ.


English

He sets forth folded with hunger, facing the wind, barefoot, plunging into the tails of ravines and rushing.

Yoruba

Ó ń lọ ní aláìjẹun, ń kojú afẹ́fẹ́, ní aláìbàtà, ń bọ́ sínú àwọn odò gbígbẹ, ó sì ń yára.

29

فَلَمَّا لَوَاهُ الْقُوتُ مِنْ حَيْثُ أَمَّهُ دَعَا فَأَجَابَتْهُ نَظَائِرُ نُحَّلٌ.


English

Then when food bent him from the direction he headed, he called, and lean ones like him answered him.

Yoruba

Nígbà tí oúnjẹ wọ́ kúrò níbí to gbèrò latí lọ, ó pe ìpè, àwọn tí ó gbẹ bíi rẹ̀ sì dá a lóhùn.

30

مُهَلَّلَةٌ شِيبُ الْوُجُوهِ كَأَنَّهَا قِدَاحٌ بِأَيْدِي يَاسِرٍ تَتَقَلْقَلُ.


English

Faces with streaks of white as if they were arrows in the hands of a gambler shaking them.

Yoruba

Àwọn ojú tí ó ní àwọ̀ funfun bí ẹni pé ọfà ni wọ́n lọ́wọ́ ònítẹtẹ tí ó ń gbọn wọn.

© , Qatru
Qatru presents public-domain classical texts and modern library works shared with permission where applicable.