وقفة
9. الباب الثالث · page 69 / 31
Yoruba:
14. Eng:
Yoruba:
15. Eng:
Yoruba:
16. Eng:
Yoruba:
And it decreases if you withhold it.
Yi o maa lekun bi o ba se n loo si
Yio si maa dinku ti o ba di mowo ti oo naa fun
awon eniyan
If you have had a taste of its sweetness,
You would have preferred learning and worked
hard.
Ti o ba jepe o to adun kan wo ninu adun mimo ri
ni
O o ba gbola fun wiwa mimo oo ba si se Igbiyanju
riri mimo
You would neither have been diverted from it by
overwhelming desire,
Nor would you have been seduced by the vanities
of this world;
Ma je ki ife inu ti o maa wa tele ki o ko airoju ba e
Masi je ki aye pelu adun yoroyoro inu re ki o ko
airoju ba e eyi ti won fe fi ko wahala ba e
You would neither have been distracted by elegant
meadows,
Nor would you have fallen in love with the finery
of the boudoir.
Ma je ki abata ere kan ki o ko igbagbe ba e
Ma si je ki obinrin elete pelu awon eso re ki o ko
igbagbe ba e debi ti oo ma wa jeran re

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru