وقفة
9. الباب الثالث · page 70 / 31
17. Eng:
Yoruba:
18. Eng:
The nutrient of the soul is the spirit of good
qualities,
And not about having eaten or drunk.
Ounje emi oun ni mimo
Kii se eyi ti onje tabi eyi ti o n mu
So devote yourself assiduously to it (knowledge)
and take it seriously,
For if Allah should grant it to you, you would
benefit greatly.
Yoruba: Dunni mo mimo yi, kio si gbaa mu pelu agbiyele
19. Eng:
Yoruba:
20. Eng:
Yoruba:
tole koko
Ti olohun ba fun e ni mimo ri wipe o fi se anfaani
And if you are granted the aptitude for it
(knowledge),
And people say; "you are very knowledgeable
indeed."
Ti olohun ba fun e ni opolopo mimo
Ti awon eniyan wa n sope onimimo ni e
Do not feel safe from Allah's question about it,
In reproach; "you had knowledge but did you put
it into practice?"
Mafi okan bale lori ibeere olohun nipa mimo re yu
Pelu ebibiran wipe onimimo looto nje o lo mimo
re yii.

Use / arrow keys to navigate pages

© , Qatru