21. Eng:
Yoruba:
22. Eng:
ADMONITION AND WISDOM
ITANIJI ATI AWON ORO OGBON
Really, the peak of knowledge is the fear Allah,
And not what is said (about you) that; "you have
become a leader."
Akori mimo ni ipaya olohun oba niti ododo
Kii se ki won maa ni wipe iwo naa je olori
The best of your clothing is that of good deeds,
But I can see you have already worn the clothing
of misdeed.
Yoruba: Eyi ti o fi n lola ju ninu aso re oun naa ni daadaa,
sugbon aso aburu ni anri lorun ti e
23. Eng:
Yoruba:
24. Eng:
Yoruba:
25. Eng:
If you do not make good use of knowledge,
It would have been better for you to be ignorant.
Nigbati ti mimo o baa se o lanfaani daada mo
O loore fun o ki o kuku je alaimokan
And if you understand should throw you into an
abyss;
I strongly wish you had not learnt at all.
Nigbati ti agboye re (mimo) ba ju o si aarin
jindojindo ina
O ma se fun o o ma se fun o nibi ohun ti o gboye ti
oo lo
You will reap ignorance as the fruit of failure (to
learn),