Chapter 1

الْمَقَامَةُ الصَّنْعَانِيَّةُ

131

لَمَا مَلَّكَ الْحُكْمَ أَهْلَ النَّقِيصَهْ


English

It would not have given rule to the deficient ones

Yoruba

Kì bá ti fún àwọn aláìpé ní àṣẹ

132

ثُمَّ قَالَ لِيَ: ادْنُ فَكُلْ


English

Then he said to me: Come closer and eat

Yoruba

Lẹ́yìn náà ó sọ fún mi pé: Súnmọ́ tòsí kí o sì jẹun

133

وَإِنْ شِئْتَ فَقُمْ وَقُلْ


English

And if you wish, stand and speak

Yoruba

Tí o bá fẹ́, dìde kí o sì sọ̀rọ̀

134

فَالْتَفَتُّ إِلَى تِلْمِيذِهِ وَقُلْتُ


English

So I turned to his student and said

Yoruba

Mo sì yí padà sí ọmọ ẹ̀kọ́ rẹ̀ mo sì sọ pé

135

عَزَمْتُ عَلَيْكَ بِمَنْ تَسْتَدْفِعُ بِهِ الْأَذَى


English

I adjure you by the One with whom you repel harm

Yoruba

Mo fi Ẹni tí o fi ń tì ìpalára sẹ́yìn be ọ

136

لَتُخْبِرَنِي مَنْ ذَا


English

To tell me who this is

Yoruba

Láti sọ fún mi ẹni tí èyí jẹ́

137

فَقَالَ: هَذَا أَبُو زَيْدٍ السَّرُوجِيُّ


English

He said: This is Abu Zayd al-Saruji

Yoruba

Ó sì sọ pé: Èyí ni Abu Seidu omo ilu Saruji

138

سِرَاجُ الْغُرَبَاءِ وَتَاجُ الْأُدَبَاءِ


English

The lamp of strangers and the crown of the learned

Yoruba

Àtùpà àwọn àlejò àti adé àwọn olùkọ́

139

فَانْصَرَفْتُ مِنْ حَيْثُ أَتَيْتُ


English

So I left from where I came

Yoruba

Mo sì padà sí ibi tí mo ti wá

140

وَقَضَيْتُ الْعَجَبَ مِمَّا رَأَيْتُ


English

And I was amazed at what I had seen

Yoruba

Mo sì ṣe ìyàlẹ́nu sí ohun tí mo rí

© , Qatru