And inhabited the lowlands,
Tí a sì ń gbé ní pẹ̀tẹ́lẹ̀,
And trod upon thorns,
Tí a sì ń rìn lórí ẹ̀gún,
And forgot our saddles,
Tí a sì gbàgbé àwọn gàárì wa,
And found pleasure in catastrophic death,
Tí a sì ń ní inú dídùn si iku apanirun,
And found the available day too slow.
Tí a sì rí ọjọ́ tó wà lọ́wọ́ bí ẹni pé ó lọ́ra.
Is there any noble consoler or generous sympathizer?
Ǹjẹ́ ari abanikedun tàbí aláàánú kan?
By He who brought me out from keilat,
Ní orúkọ Ẹni tó mú mi jáde nínú keila,
I have become impoverish,
Mo ti di olòṣì,
Not owning a night's shelter.
Tí n kò ní ibùjókòó fún alẹ́ kan.
Al-Harith bin Hammam said:
Harisu ọmọ Hammam sọ pé: