Chapter 10

الْمَقَامَةُ الرَّحْبِيَّةُ

91

فَنَقَدَهُ الْوَالِي عِشْرِينَ.


English

So the governor paid him twenty.

Yoruba

Nítorí náà gómìnà náà san ogún fún un.

92

وَوَزَّعَ عَلَى وَزَعَتِهِ تَكْمِلَةَ خَمْسِينَ.


English

And distributed among his guards the completion of fifty.

Yoruba

Ó sì pín láàrín àwọn olùṣọ́ rẹ̀ ìpín tó kù nínú àádọ́ta.

93

وَرَقَّ ثَوْبُ الْأَصِيلِ.


English

And the cloth of the evening is becoming low

Yoruba

Aṣọ òru tí ń fẹlẹ,

94

وَانْقَطَعَ لِأَجْلِهِ صَوْبُ التَّحْصِيلِ.


English

And for his sake, the path of achievement was cut off.

Yoruba

Àti pé nítorí rẹ̀, a gé ọ̀nà ìgbà owó jọ kúrò.

95

فَقَالَ: خُذْ مَا رَاجَ.


English

So he said: Take what is in available

Yoruba

Nítorí náà ó sọ pé: Mú ohun tí ó tí wa

96

وَدَعْ عَنْكَ اللَّجَاجَ.


English

And leave behind the obstinacy.

Yoruba

Kí o sì fi agídí sílẹ̀.

97

وَعَلَيَّ فِي غَدٍ أَنْ أَتَوَصَّلَ.


English

And tomorrow, it's upon me to arrange.

Yoruba

Àti lọ́la, ó jẹ́ ojúṣe mi láti ṣe ètò.

98

إِلَى أَنْ يَنِضَّ لَكَ الْبَاقِي وَيَتَحَصَّلَ.


English

Until the remainder is liquefied for you and obtained.

Yoruba

Títí tí ìyókù yóò fi jáde fún ọ àti kí a gbà á.

99

فَقَالَ الشَّيْخُ: أَقْبَلُ مِنْكَ عَلَى أَنْ أُلَازِمَهُ لَيْلَتِي.


English

The old man said: I accept from you on condition that I stay with him tonight.

Yoruba

Àgbàlagbà náà sọ pé: Mo gbà lọ́wọ́ rẹ pẹ̀lú ìdí pé èmi yóò dúró pẹ̀lú rẹ̀ lálẹ́ yìí.

100

وَيَرْعَاهُ إِنْسَانُ مُقْلَتِي.


English

And the pupil of my eye will watch over him.

Yoruba

Àti pé ọmọ ojú mi yóò ṣọ́ ọ.

© , Qatru