Chapter 2

الْمَقَامَةُ الْحُلْوَانِيَّةُ

11

وَأَسْتَسْقِي الْوَبْلَ وَالطَّلَّ.


English

seeking heavy rain and light drizzle,

Yoruba

tí ó ń wá òjò àrà àti erì,

12

وَأَتَعَلَّلُ بِعَسَى وَلَعَلَّ.


English

and consoling myself with 'maybe' and 'perhaps'.

Yoruba

tí ó sì ń tù ara rẹ̀ nínú pẹ̀lú 'bóyá' àti 'ó ṣe é ṣe'.

13

فَلَمَّا حَلَلْتُ حُلْوَانَ.


English

When I arrived at Hulwan,

Yoruba

Nígbà tí mo dé Ḥulwán,

14

وَقَدْ بَلَوْتُ الْإِخْوَانَ.


English

having tested brothers,

Yoruba

lẹ́yìn tí mo ti dán àwọn arákùnrin wò,

15

وَسَبَرْتُ الْأَوْزَانَ.


English

probed measures,

Yoruba

Ti mo sì tún wádìí àwọn òsùwọ̀n,

16

وَخَبِرْتُ مَا شَانَ وَزَانَ.


English

and experienced what disgraces and adorns,

Yoruba

kí n sì ní ìrírí ohun tí ó ń ba ni jẹ́ àti èyí tí ó ń ṣe ọ̀ṣọ́,

17

أَلْفَيْتُ بِهَا أَبَا زَيْدٍ السَّرُوجِيَّ يَتَقَلَّبُ فِي قَوَالِبِ الِانْتِسَابِ.


English

I found there Abu Zayd as-Saruji, shifting between forms of affiliation,

Yoruba

Mo rí Abú Seidu omo ilu Sarújì níbẹ̀, tí ó ń yí padà láàárín àwọn ọ̀nà ìbágbépọ̀,

18

وَيَخْبِطُ فِي أَسَالِيبِ الِاكْتِسَابِ.


English

and stumbling through means of acquisition.

Yoruba

tí ó sì ń kọsẹ̀ láàárín àwọn ọ̀nà ìjẹ àti mímú,

19

فَيَدَّعِي تَارَةً أَنَّهُ مِنْ آلِ سَاسَانَ.


English

Sometimes he would claim to be from the family of Sasan,

Yoruba

Nígbà míràn yóò máa sọ pé ó wá láti ìdílé Sásán,

20

وَيَعْتَزِي مَرَّةً إِلَى أَقْيَالِ غَسَّانَ.


English

and other times he would trace his lineage to the chiefs of Ghassan.

Yoruba

nígbà míràn yóò sì máa ṣàfihàn pé ó jẹ́ ọmọ àwọn olórí Ghassán.

© , Qatru