So for the beauty of his tools,
Nítorí ẹwà irinṣẹ́ rẹ̀,
his flaws was covered,
Ni àwọn eeyan n fí n bo àwọn àbùkù rẹ̀ mọ́lẹ̀.
And for the breadth of his narration,
Fún ìtàn rẹ̀ tí ó tóbi,
one would yearn to see him.
ènìyàn yóò máa fẹ́ láti rí i.
And for the charm of his wit,
Fún agbára ọgbọ́n rẹ̀,
one would refrain from opposing him.
ènìyàn yóò fàsẹ́yìn láti tako o.
And for the sweetness of his expression,
Fún adùn ọ̀rọ̀ rẹ̀,
he was granted his desire.
a fún un ní ohun tí ó fẹ́.
So I clung to the ends of his robe,
Nítorí náà mo di mọ́ eti aṣọ rẹ̀,
for the uniqueness of his manners.
nítorí àwọn ìwà rẹ̀ tí kò ṣe é fiwé.