Chapter 4

الْمَقَامَةُ الدِّمْيَاطِيَّةُ

171

إِلَى أَنْ غُمِرَا بِالنُّحْلَانِ.


English

Until they were overwhelmed with gifts.

Yoruba

Títí tí ẹ̀bùn fi bò wọ́n mọ́lẹ̀.

172

وَاتُّخِذَا مِنَ الخُلَّانِ.


English

And were taken as close friends.

Yoruba

A sì mú wọn bí ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́.

173

وَكُنَّا بِمَعْرَسٍ نَتَبَيَّنُ مِنْهُ بُنْيَانَ القُرَى.


English

We were at a resting place from which we could see the buildings of villages.

Yoruba

A wà ní ibi ìsinmi kan tí a ti lè rí àwọn ilé ìlú náà.

174

وَنَتَنَوَّرُ نِيرَانَ القِرَى.


English

And discern the fires of hospitality.

Yoruba

A sì ń rí iná àlejò.

175

فَلَمَّا رَأَى أَبُو زَيْدٍ امْتِلَاءَ كِيسِهِ.


English

When Abu Zayd saw his purse was full.

Yoruba

Nígbà tí Abu Seidu rí i pé àpò rẹ̀ ti kún.

176

وَانْجِلَاءَ بُؤْسِهِ.


English

And his misery had cleared.

Yoruba

Tí òsì rẹ̀ sì ti kúrò.

177

قَالَ لِي: إِنَّ بَدَنِي قَدِ اتَّسَخَ.


English

He said to me: My body has become dirty.

Yoruba

Ó sọ fún mi pé: Ara mi ti dọtí.

178

وَدَرَنِي قَدْ رَسَخَ.


English

And my grime has been firm

Yoruba

Èérí sì ti lẹ̀ mọ́ mi.

179

أَفَتَأْذَنُ لِي فِي قَصْدِ قَرْيَةٍ لِأَسْتَحِمَّ.


English

Do you permit me to go to a village to bathe?

Yoruba

Ṣé o yóò fún mi láààyè láti lọ sí ìlú kan láti wẹ̀?

180

وَأَقْضِيَ هَذَا المُهِمَّ؟


English

And accomplish this important matter?

Yoruba

Kí n sì ṣe ohun pàtàkì yìí?

© , Qatru