And like one soul in the harmony of desires.
Àti bí ẹ̀mí kan ní ìbáramu ìfẹ́.
And with that, we traveled swiftly,
Pẹ̀lú èyí, a ń rin kíákíá,
And we departed not but each on his she-camel .
A kò sì ń kúrò àyàfi igbati kaluku gun abo-rankunmi.
And when we alighted at a stopping place,
Nígbà tí a bá dé ibi ìsinmi,
Or arrived at a watering place,
Tàbí tí a dé ibi abata kan,
We snatched a brief stay,
A simi fun ìgbà díẹ̀ ni aye naa,
And did not prolong our stay.
A kò sì ń pẹ́ níbẹ̀.
Then it occurred to us to set our mounts in motion,
Lẹ́yìn náà ó wá sí wa lọ́kàn láti mú àwọn ẹṣin wa rìn,
In a night youthful in its prime,
Ní alẹ́ tí ó ní agbára ìgbà èwe,
Raven-black in its skin.
Tí ó dúdú bí ẹyẹ ìwò ní àwọ̀.