Al-Harith bin Hammam narrated, saying:
Harisu ọmọ Hammam sọ̀rọ̀, ó wí pé:
When I mounted the hump of exile
Nígbà tí mo joko sorí ràkúnmí ìrìn ajo
And poverty distanced me from my peers
Tí òṣì sì mumi jìnnà sí àwọn ẹlẹgbẹ́ mi
The vicissitudes of time tossed me
Àwọn ìyípadà àkókò ju mi
To Sana'a of Yemen
Sí Sana'a ní Yemen
I entered it with an empty sack
Mo wọ ilu naa pẹ̀lú àpò òfìfo
Clearly destitute
Ní irisi aláìní
Possessing no provisions
Mi ò ní ohun èlò
And finding not in my bag a morsel
Bẹ́ẹ̀ ni n kò rí oúnjẹ kékeré kan nínú àpò mi
So I began to roam its streets like one bewildered
Nígbà náà ni mo bẹ̀rẹ̀ sí ní rìn káàkiri àwọn òpópóna rẹ̀ bí ẹni tí orí ń yí