Chapter 11

الْمَقَامَةُ السَّاوِيَّةُ

1

حَدَّثَ الحَارِثُ بنُ هَمَّامٍ قَالَ: آنَسْتُ مِنْ قَلْبِي القَسَاوَةَ


English

Al-Harith bin Hammam narrated, saying: I sensed hardness in my heart

Yoruba

Hárìsù ọmọ Hammám sọ̀rọ̀ pé: Mo rí líle ọkàn nínú àyà mi

2

حِينَ حَلَلْتُ سَاوَةَ


English

When I arrived at Sawah

Yoruba

Nígbà tí mo dé ìlú Sáwà

3

فَأَخَذْتُ بِالخَبَرِ المَأْثُورِ فِي مُدَاوَاتِهَا بِزِيَارَةِ القُبُورِ


English

So I followed the traditional wisdom of treating it by visiting the graves

Yoruba

Nítorí náà, mo tẹ̀lé ọgbọ́n àtọwọ́dọ́wọ́ láti wò ó sàn nípa lílọ́ sí ibojì

4

فَلَمَّا صِرْتُ إِلَى مَحَلَّةِ الأَمْوَاتِ وَكِفَاتِ الرُّفَاتِ


English

When I reached the dwelling place of the dead and the repository of remains

Yoruba

Nígbà tí mo dé ibùgbé àwọn òkú àti ibi ìpamọ́ egungun

5

رَأَيْتُ جَمْعاً عَلَى قَبْرٍ يُحْفَرُ وَمَجْنُوزٍ يُقْبَرُ


English

I saw a gathering at a grave being dug and a deceased being buried

Yoruba

Mo rí ọpọ ènìyàn ní ibi tí wọ́n tí ń gbẹ́ ibojì kan tí wọ́n sì ńsin òkú kan

6

فَانْحَزْتُ إِلَيْهِمْ مُتَفَكِّراً فِي المَآلِ مُتَذَكِّراً مَنْ دَرَجَ مِنَ الآلِ


English

So I joined them, contemplating the final fate and remembering those of my family who had passed

Yoruba

Mo sì dàpọ̀ mọ́ wọn, mo ńrònú nípa ìgbẹ̀hìn ayé, mo ńrántí àwọn ará ilé mi tó ti kú

7

فَلَمَّا أَلْحَدُوا المَيِّتَ وَفَاتَ قَوْلُ لَيْتَ


English

When they laid the deceased in the grave and the time for 'if only' had passed

Yoruba

Nígbà tí wọ́n ti tẹ́ òkú sí ibojì tí àkókò 'ìbáà ṣe' sì ti kọjá

8

أَشْرَفَ شَيْخٌ مِنْ رَبَاوَةٍ مُتَخَصِّراً بِهِرَاوَةٍ وَقَدْ لَفَّعَ وَجْهَهُ بِرِدَائِهِ وَنَكَّرَ شَخْصَهُ لِدَهَائِهِ


English

An elder appeared from a hill, leaning on a staff, having wrapped his face with his cloak and disguised his persona through his cunning

Yoruba

Àgbàlagbà kan yọjú láti orí òkè, ó fi ọ̀pá tì ara, ó si fi aṣọ bo ojú rẹ̀, ó sì pa ara rẹ̀ mọ́ pẹ̀lú ọgbọ́ń ète rẹ

9

فَقَالَ: لِمِثْلِ هَذَا فَلْيَعْمَلِ العَامِلُونَ


English

He said: For the end like this, let the workers work

Yoruba

Ó sọ pé: Fún irú ìgbẹ̀yìn yí ni kí àwọn oníṣẹ́ ṣiṣẹ́

10

فَادكِرُوا أَيُّهَا الغَافِلُونَ


English

So remember, O you who are heedless

Yoruba

Nítorí náà, ẹ rántí, ẹ̀yin tí ẹ ń ṣe àìmọ̀kan

© , Qatru