Chapter 11

الْمَقَامَةُ السَّاوِيَّةُ

51

ستُذْري الدم لا الدمع.


English

You will shed blood, not tears.

Yoruba

Ìwọ yóó sún ẹ̀jẹ̀, kìí ṣe omije.

52

إذا عاينْتَ لا جمع.


English

When you witness that no group.

Yoruba

Nígba tí o bá rí pe kò sí ìjọ kan.

53

يقي في عرصةِ الجمع.


English

Will protect in the assembly of resurrection

Yoruba

Tí yóò ṣọ ní àgbègbè ìgbènde

54

ولا خالَ ولا عم.


English

No uncle, no paternal cousin.

Yoruba

Kò sí ọmọ́ ìyá, kò sì ọmọ bàbá

55

كأني بك تنحطّ.


English

As if I saw you descending

Yoruba

Bíi pé emi rí ọ tí o ń lọlẹ.

56

الى اللحدِ وتنْغطّ.


English

To the grave, you sinking in it.

Yoruba

Sí ibojì, o jìn sínú rẹ.

57

وقد أسلمك الرهطْ.


English

The group has surrendered you.

Yoruba

Ẹgbẹ́ náà ti fi ọ́ sílẹ̀.

58

الى أضيقَ من سم.


English

To a space narrower than a needle.

Yoruba

Sí ààyè tó kéré ju ìla abẹrẹ́ lọ.

59

هناك الجسم ممدود.


English

There, the body is stretched out.

Yoruba

Níbẹ̀, ara náà ti dí títẹ

60

ليستأكِلَه الدود.


English

For the worms to consume it.

Yoruba

Fún àwọn kòkòrò làti jẹ

© , Qatru