The Nisibis Maqama
Ìtàn Nisibis
Al-Harith ibn Hammam narrated: Iraq suffered a drought in a particular year due to the failure of the rain clouds.
Harisu omo Hammam sọ pé: Ilẹ̀ Iraki gbẹ ni ọdún kan láti inú ìgbóná nítorí àìsí òjò.
And the travelers spoke of the fertile lands of Nasibin and the prosperity of its people of enjoyment.
Àwọn arìnrìn-àjò sọ̀rọ̀ nípa ilẹ̀ olọọra Nasibin àti ìgbádùn àwọn ènìyàn rẹ̀ òní àṣeyọrí.
So I mounted a horse and took a spear.
Nítorí náà, mo gun ẹṣin mo sì mú ọ̀kọ̀.
And I traveled from land to land, drawn by the highs and lows.
Mo sì rìn láti ilẹ̀ kan sí ilẹ̀ mìíràn, tí àwọn ibi gíga àti ibi petele ń fa mí.
Until I reached it, tired man on a tired camel
Títí tí mo fi dé ibẹ̀, lẹni tóò rẹ̀ lórí ràkúnmí tó tí rẹ
When I settled in its fertile land and took my share of its pasture.
Nígbà tí mo so kalẹ̀ ní ilẹ̀ oloora rẹ̀ mo sì gba ipin mi nínú pápá rẹ̀.
I decided to lay down my roots there and make its people my neighbors.
Mo pinnu láti gbé ibùgbé mi níbẹ̀ kí n sì ṣe àwọn ènìyàn rẹ̀ ní aládùúgbò mi.
Until the barren year comes to life and the land of my people is renewed.
Títí tí ọdún ọgbẹ yóò fi yè àti ilẹ̀ àwọn ènìyàn mi yóò tún di tuntun
By Allah, my eyes did not close in sleep, nor did my night turn into day.
Nítorí Ọlọ́run, ojú mi kò pa mọ́ nínú oorun, alẹ́ mi kò sì yí padà sí ọjọ́.