Chapter 19

الْمَقَامَةُ الْنصيبية

51

فارجِعوا أدراجكُم.


English

So return to your places.

Yoruba

Nítorí náà, ẹ padà sí ibi tí ẹ̀ tí ń bọ̀.

52

وانضوا انزِعاجكُم.


English

And dispel your worries.

Yoruba

Àti pé ẹ̀ yọ ìbẹ̀rù yín kúrò.

53

فكأنْ قد غَدا وراح.


English

As if he had come and gone.

Yoruba

Bí ẹni pé ó ti wá, ó sì ti lọ.

54

وساقاكُم الراح.


English

And brought you comfort.

Yoruba

Ó sì mú ìtùnú wá fún yín.

55

فأعظَمنا بشراه.


English

We greatly rejoiced at his good news.

Yoruba

A yọ̀ gidigidi fún ìròyìn rere rẹ̀.

56

واقترحنا أنْ نراه.


English

And we suggested to see him.

Yoruba

Àti pé a pinu láti rí i.

57

فدخلَ مؤذِناً بِنا.


English

So he entered, announcing us.

Yoruba

Nítorí náà, ó wọlé, ó sì kéde wa.

58

ثمّ خرج آذِناً لنا.


English

Then he came out, permitting us.

Yoruba

Lẹ́yìn náà, ó jáde, ó sì fún wa ní àṣẹ.

59

فلَقينا منه لَقًى.


English

We met him (Abu Zayd) lying down

Yoruba

A rí (Abu Seidu) ní idubulẹ sùn

60

ولِساناً طلْقاً.


English

And a fluent tongue.

Yoruba

Pẹlu pe ahọ́n rẹ ń sọ̀rọ̀ dáadáa.

© , Qatru