Chapter 25

الْمَقَامَةُ الْكرجية

1

حَكَى الحارِثُ بن همّامٍ قال: شَتوتُ بالكَرجِ لدَينٍ أقتَضيهِ. وأربٍ أقضيهِ.


English

Al-Harith bin Hammam narrated: I wintered in Karaj to collect a debt and fulfill a need.

Yoruba

Harisu ọmọ Hammam sọ pé: Mo lo ìgbà òtútù ní Karaji láti gba gbèsè àti láti yanjú bukaata kan.

2

فبَلَوتُ من شِتائِها الكالِحِ. وصِرها النافِحِ.


English

So I experienced its harsh winter and biting cold.

Yoruba

Nítorí náà, mo ní irírí òtútù rẹ̀ tí ó le àti ìtútù tí ó múra.

3

ما عرَفَني جُهدَ البلاءِ. وعكَفَ بي على الاصطِلاءِ.


English

It introduced me to the hardship of affliction and kept me by the fire.

Yoruba

Ó mú mi mọ̀ ìṣòro ìjàmbá àti ó mú mi dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ iná.

4

فلم أكُن أُزايلُ وِجاري. ولا مستوقَدَ ناري.


English

I did not leave my shelter or my kindling place of fire.

Yoruba

Mi ò fi ilé mi tàbí arò iná mi sílẹ̀.

5

إلا لضرورةٍ أُدفَعُ إليها. أو إقامةِ جماعةٍ أحافِظُ عليهِ.


English

Except for a necessity that compelled me or to maintain a gathering.

Yoruba

Ayafi fún àìní kan tí ì jẹ òranyàn làti wá, tàbí láti ṣètò ìpàdé kan.

6

فاضطُررتُ في يومٍ جوُّهُ مُزمهِرٌ. ودُجنهُ مُكفَهِرٌ.


English

So I was forced on a day with a severe cold and gloomy sky.

Yoruba

Nítorí náà, mo ní láti jáde ní ọjọ́ tí òtútù rẹ̀ le àti ọ̀run rẹ̀ dúdú.

7

إلى أن برزتُ من كِناني. لمُهِمٍ عناني.


English

Until I emerged from my shelter for an urgent matter.

Yoruba

Títí tí mo fi jáde kúrò ní ibi ààbò mi fún ọ̀ràn pàtàkì kan.

8

فإذا شيخٌ عاري الجِلدةِ. بادي الجُردةِ.


English

There I saw an old man, bare-skinned and exposed.

Yoruba

Níbẹ̀ ni mo rí àgbàlagbà kan, tí kò ní aṣọ lórí ara rẹ̀, àrà rẹ n hàn.

9

وقدِ اعتمَّ بريطَةٍ. واستثْفَرَ بفُويطَةٍ.


English

He had wrapped a cloth around his head and girded himself with a piece of cloth.

Yoruba

Ó ti dì aṣọ kan yíká orí rẹ̀, ó sì tún dì ara rẹ̀ pẹ̀lú aṣọ kan.

10

وحوالَيهِ جمعٌ كَثيفُ الحواشي. وهو ينشِدُ ولا يُحاشي:


English

And around him was a dense crowd, and he was reciting without hesitation:

Yoruba

Àti pé ní àyíká rẹ̀ ni àwọn ènìyàn púpọ̀ wà, ó sì ń kọ orin láìsí ìdẹ́kun:

© , Qatru